Pamela Adie

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Pamela Adie
Ọjọ́ìbíCalabar, Cross River State, Nigeria
Orílẹ̀-èdèNigerian
Iléẹ̀kọ́ gígaWebster University
University of Wisconsin
University of Baltimore
Iṣẹ́activist, public speaker and filmmaker
Gbajúmọ̀ fúnUnder the Rainbow, Ìfé

Pamela Adie jẹ́ ònkàtàn, olùbá ọ̀pọ̀ èrò sọ̀rọ̀, ato ajìjàn-n-gbara fún ẹ̀tọ́ àwọn LGBT ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Pamela di ìlú mọ̀ọ́ká pẹ̀lú akitiyan rẹ̀ lórí ẹ̀tọ́ awọ LGBTQ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[1] Iṣẹ́ ìwádí rẹ̀ ni ó dá lé LGBT rights in Nigeria lọ́rísiríṣi, lára ìwé rẹ̀ tí ó ti kọ ni Under the Rainbow eré tí ó fi ìrírí rẹ̀ hàn.[2] lára eré rẹ̀ ni ó ti ṣe àfihàn eré tí ó jọ mọ́ bí Obìnrin ṣe ń ṣọkọ obìnrin tí wọ́n pe ní Ìfé . Òun ni Adarí agbà fún ajọ tí kìí ṣe ti ìjọba tí wọ́n pè ní Equality Hub.[3]

Ìgbé ayé rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Lóòtọ́ ni ó ṣe ìgbéyàwó ọkọ rẹ̀ ọkùnrin kan, amọ́ ó sọ ní gbangba wípé òlúfẹ́ obìrin bíi tìrẹ̀ ni oun tí àwọn gẹ̀ẹ́sì ń pe ní lesbian, ìkéde yí ni ó ṣe ní ọdún 2011 nígbà tí ó ṣe ìpàdé pẹ̀lú àwọn ẹbí rẹ̀.[4] She hails from Calabar, Cross River State.[5]

Iṣẹ́ rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Pamela kẹ́kọ́ nípa ìmọ̀ òfin ní ilé-ẹ̀kọ́ Webster University tí ó sì parí ẹ̀kọ́ ọ̀mọ̀wé Masters degree rẹ̀ ní ilé-ẹ̀kọ́ University of Baltimore. Ó tún kẹ́kọ́ gboyè akọ́kọ́ ní inú ìmọ̀ ìṣàkóso okòwò Business administration láti ilé-ẹ̀kọ́ University of Wisconsin-Superior.[1] Ó tún lọ kẹ́kọ́ nípa ẹ̀tọ́ LGBT tí ó sìntibẹ̀ di obìrin akọ́kọ́ntí ó jẹ́ a jànfẹ́tó àwọ LGBT ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Bá kan náà ni ó kópa nibi àpérò okòwò àgbáyé ní ọdún 2017 tí ó sì sọ̀rọ̀ nípa ẹ̀tọ́ àwọn LGBT ní inú àpérò náà níbi tí ó ti sọ̀rọ̀ nípa pàtàkì Àwọn LGBT ní ibi iṣẹ́.[6]

Ó ti kọ ìtàn tí wọn ti sọ di eré tí ó sí tún jẹ́ adarí eré náà tí wọ́n pe ní Under te Rainbow, eré tí ó da lé bí Obìnrin ṣe ń ṣọkọ obìnrin, irúfẹ́ akọ́kọ́ irú rẹ̀ tí wọn yóò gbé jáde ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Eré yí ni ó da lè ìṣẹ̀lẹ̀ ìgbésí ayé rẹ̀. [7][8] Ní ọdún 2019, wọ́n yàn fún amì-ẹ̀yẹ Mary Chinwa Award tí orúkọ nrẹ̀ sì jáde níbiẹ̀ ní ọdún 2018.[9]

Ìfé[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Pamela fi èrò rẹ̀ han nípa gbígbé eré kan jáde tí yóò da lè bí Obìnrin ṣe ń ṣọkọ obìnrin tí ó lè ní Ìfé. Orísiríṣi àríwísí ni ó wáyé lórí eré tí ó ní oun fẹ́ gbé jáde náà látàrí bí ìjọba orílẹ̀-èdè Nàìjíríà lábẹ́ ìṣèjọba Goodluck Jonathan ti fòfin de étọ́ LGBT. Oun ati gbajú-gbajà òṣèré Uyaiedu Ikpe-Etim pẹ̀lú ajọ Equality Hub ni wọ́n jọ pawọ́pọ̀ gbé eré náà jáde.[10] Eré yí ni ó jẹ́ eré akọ́kọ́ tí yóò da lè bí Obìnrin ṣe ń ṣọkọ obìnrin

tabí LGBT ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[11][12] Eré náà rí ìdádúró oríṣiríṣi látàrí ayẹ̀wó tó gbórín lọ́wọ́ àjọ tí ó ń ṣe ayẹ̀wò eré sì ni má agbéléwò ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Kódà àjọ náà fi àtimọ́lé dún kòkokò mọ́ àwọn òṣèré náà bí wọ́n bá gbé eré náà jáde.[13]

Àwọn ìtọ́ka sí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. 1.0 1.1 "Pamela Adie – Chief Servant/Executive Director – The Equality Hub" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-09-15. 
  2. "Nigeria’s first lesbian documentary". africasacountry.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-09-15. 
  3. "The Equality Hub – …a network for equality" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-09-15. 
  4. Admin. "Cross River Born Lesbian Sets Wedding Date With Partner (See Photos)". Paradise News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2021-08-03. Retrieved 2020-09-15. 
  5. "Nigerian lesbian, Pamela Adie, tells her story in new documentary". NoStringsNG – Voice of LGBTQ+ Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-04-07. Retrieved 2020-09-15. 
  6. "Pamela Adie" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2020-11-26. Retrieved 2020-09-15. 
  7. "Pamela Adie's Under the Rainbow Is Nigeria's First Documentary About Being Lesbian | Watch Teaser". Brittle Paper (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-07-29. Retrieved 2020-09-15. 
  8. "Nigeria's first lesbian documentary film is finally here – Rights Africa – Equal Rights, One Voice!". Rightsafrica.com. 2019-07-03. Retrieved 2019-07-08. 
  9. Times, The Rustin (2019-10-14). "Nigerian activist Pamela Adie is nominated for the first Mary Chirwa Award for Courageous Leadership". The Rustin Times (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-09-15. 
  10. Ike, Joanne (2020-08-24). "Nigeria's first lesbian movie, Ìfé, is set to change stereotypes » YNaija". YNaija (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-08-28. 
  11. "'Ife', Nigeria's first lesbian movie, goes online to beat NFVCB". TheCable Lifestyle (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-08-06. Retrieved 2020-08-28. 
  12. Salaudeen, Aisha. "Nollywood film about two women in love tackles homophobia". The Philadelphia Tribune (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-08-28. 
  13. "The Nigerian filmmakers risking jail with lesbian movie Ife" (in en-GB). BBC News. 2020-09-14. https://www.bbc.com/news/world-africa-54070446.