Plánẹ̀tì
Jump to navigation
Jump to search
Plánẹ́tì gege bi Egbeirepo imo Ofurufu Kakiriaye (IAU) se se'tumo re je ohun oke-orun ti o n yi irawo ka tabi aloku orun ti tiwuwosi re je ki o ri roboto, ti ko tobi pupo lati gba yiyo igbonainuikun (anthothermonuclear fusion) laaye ninu re, ti o si ti gba awon orisirisi idena kura cartele de santata lona ti o n gba koja.
Awon Planeti ti o wa ninu Ètò Òòrùn[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Gege bi (IAU) se so, planeti mejo ni won wa ninu ètò òòrùn. Awon niwonyi bi won se njinna si Òòrùn:
Èdè Yorùbá[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Èdè Gẹ̀ẹ́sì[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
![]() |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
|