Jump to content

Plánẹ́tì

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Planeti)
Àwọn pílánẹ́ẹ̀tì tó wà nínú àgbájọ oòrùn

Pílánẹ́tì gẹ́gẹ́ bí i Ẹgbẹ́ìrẹ́pọ̀ ìmọ̀ Òfurufú Káàkiriayé (IAU) ṣe ṣè'tumọ̀ rẹ̀ jẹ́ ohun òkè-ọrùn tí ó ń yí ìrànwọ́ ká tàbí aloku ọ̀run tí tíwúwosí rẹ̀ jẹ́ kí ó rí róbótó, tí kò tóbi púpọ̀ láti yíyọ́ ìgbónáinúikùn (anthothermonuclear fusion) láàyè nínú rẹ̀, tí ó sì ti gba àwọn oríṣiríṣi ìdènà kúra cartele dé santata lọ́nà tí ó ń gbà kọjá.

Àwọn Pílánẹ́tì tí ó wà nínú Ètò Òòrùn

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Gẹ́gẹ́ bí (IAU) ṣe sọ, pílánẹ́tì mẹ́jọ ni wọ́n wà nínú ètò òòrùn. Àwọn nìwọ̀nyìí bí wọ́n ṣe ń jìnnà sí Òòrùn:

  1. (☿) Mẹ́rkúríù
  2. (♀) Àgùàlà
  3. (🜨) Ilẹ̀-ayé
  4. (♂) Mársì
  5. (♃) Júpítérì
  6. (♄) Sátúrnù
  7. (♅) Úránù
  8. (♆) Nẹ́ptúnù
  1. ☿ Mercury
  2. ♀ Venus
  3. 🜨 Earth
  4. ♂ Mars
  5. ♃ Jupiter
  6. ♄ Saturn
  7. ♅ Uranus
  8. ♆ Neptune