Nkhensani Manganyi: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Content deleted Content added
kNo edit summary
Ìlà 1: Ìlà 1:
'''Nkhensani Manganyi''' jẹ́ òṣèré àti aránṣọ ni orílẹ̀-èdè [[South Áfríkà]].
'''Nkhensani Manganyi''' jẹ́ òṣèré àti aránṣọ ni orílẹ̀-èdè [[South Africa]].

== Iṣẹ́ rẹ̀ ==
== Iṣẹ́ rẹ̀ ==
Ìlà 5: Ìlà 5:
Ilẹ̀ iṣẹ́ náà má ń ṣe gíláàsì fún [[ojú]]<ref>{{Cite news|url=http://www.news24.com/Archives/City-Press/Winning-Women-Renaissance-fashion-guru-20150430|title=Winning Women: Renaissance fashion guru|work=News24|access-date=2017-03-08}}</ref>. Díè nínú àwọn iṣẹ́ rẹ sì wà ní ''Fashion Institute of Technology'' níbi tí won tí se ìfihàn rẹ níbi ayẹyẹ [[Black Fashion Designers]] ni ọdún 2016<ref>{{Cite news|url=http://nymag.com/thecut/2016/12/black-designers-finally-get-a-museum-exhibit.html|title=Black Designers Finally Get a Museum Exhibit|last=Peoples|first=Lindsay|work=The Cut|access-date=2017-03-08|language=en}}</ref><ref>{{Cite web|url=https://www.fitnyc.edu/museum/exhibitions/black-fashion-designers.php|title=Black Fashion Designers {{!}} Fashion Institute of Technology|website=www.fitnyc.edu|language=en|access-date=2017-03-09}}</ref>.

Manganyi tí kópa nínú àwọn eré bíi ''Legend of the Hidden City'', ''Tarzan'', ''The Epic Adventures ati Kickboxer 5'' àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.

Ní ọdún 2003, ó se adájọ́ fún ètò ''Pop Star'' tí won ṣẹ́ lórílẹ̀ èdè [[South Áfríkà]].
Ní ọdún 2003, ó se adájọ́ fún ètò ''Pop Star'' tí won ṣẹ́ lórílẹ̀ èdè [[South Africa]].

== Àwọn Ìtọ́kasí ==
== Àwọn Ìtọ́kasí ==

Àtúnyẹ̀wò ní 16:55, 25 Oṣù Kẹ̀wá 2020

Nkhensani Manganyi jẹ́ òṣèré àti aránṣọ ni orílẹ̀-èdè South Africa.

Iṣẹ́ rẹ̀

Ní ọdún 2000, Manganyi bẹ̀rẹ̀ ilé-iṣẹ́ aránṣọ tirẹ̀ tí ó pè ní Stoned Cherrie.[1][2] Ìkan lára àwọn aṣọ tí ó rán gbáyi láti ilé iṣẹ́ ìròyìn Drum.[3] Ilẹ̀ iṣẹ́ náà má ń ṣe gíláàsì fún ojú[4]. Díè nínú àwọn iṣẹ́ rẹ sì wà ní Fashion Institute of Technology níbi tí won tí se ìfihàn rẹ níbi ayẹyẹ Black Fashion Designers ni ọdún 2016[5][6]. Manganyi tí kópa nínú àwọn eré bíi Legend of the Hidden City, Tarzan, The Epic Adventures ati Kickboxer 5 àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. Ní ọdún 2003, ó se adájọ́ fún ètò Pop Star tí won ṣẹ́ lórílẹ̀ èdè South Africa.

Àwọn Ìtọ́kasí