Rahmon Ade Bello

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Rahmon Ade bello
11th Vice Chancellor of the University of Lagos
In office
May 2012 – November 2017
acting May 2012 – November 2012
DeputyProfessor Babajide Alao (academic)
Professor Duro Oni (management)
AsíwájúBabatunde Adetokunbo Sofoluwe
Arọ́pòOluwatoyin Ogundipe
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbíÀdàkọ:Birth month and age
Ogun State, Nigeria
Ẹgbẹ́ olóṣèlúNon-Partisan

Rahmon Ade Bello (tí wọ́n bí ní oṣù kẹwàá ọdún 1948) jẹ́ Ọ̀jọ̀gbọ́n Chemical Engineering ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, Aṣàákoso Ẹ̀kọ́ àti Vice Chancellor tẹ́lẹ̀ rí ní Fásíìtì Ẹ̀kó ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.[1][2][3]

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n bí Rahmon ní oṣù kẹwàá ọdún 1948 ní Ìpínlẹ̀ Ògùn, ní apá Ìwọ̀-oòrùn ilẹ̀ Nàìjíríà. Ilé-ìwé Egbado College ní Ilaro tó wà ní ìpínlè Ògùn ni ó lọ. Ó tẹ̀síwájú láti gboyè ẹ̀kọ́ ní Polytechnic of Ibadan, níbi tí ó ti gba oyè OND nínú ìmọ̀ mechanical engineering. Ní ọdún1974, ó gba oyè B.Sc. nínú ìmọ̀ chemical engineering bákan náà láti Obafemi Awolowo University. Ó sì tún ní oyè ẹ̀kọ́ ti master's nínú chemical engineering láti University of Waterloo àti Ph.D. láti ilé-ẹ̀kọ́ kan náà.[4]

Iṣẹ́ tó yàn láàyò[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n yàn án gẹ́gẹ́ bí í igbá kejì aṣàáko ti Fáṣítì Èkó ní oṣù karùn-ún ọdún 2012 lẹ́yìn ikú òjijì ọ̀jọ̀gbọ́n Babatunde Adetokunbo Sofoluwe, tí ó wà ní ipò náà, àrùn ọkàn ló ṣekú pá á ní ọdún 2012.[5][6][7] Ní oṣù kọkànlá ọdún 2012, wọ́n jẹ́rìí sí pé Rahmon ni Vice Chancellor ni Fáṣítì, ipò tí ó wà títí di oṣù Kejìlá ọdún 2017.[8][9][10]

Ó wà lára oríṣiríṣi iṣẹ́ ọjọ̀gbọ́n bí í Nigeria Academy of Nigeria, Nigerian Society of Engineers, Nigerian Society of Chemical Engineers àti COREN.

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Alleged Training of Snipers: NHRC holds emergency meeting over OBJ's letter - Vanguard News". Vanguard News. 
  2. "Senate committee queries UNILAG on IGR". The Punch - Nigeria's Most Widely Read Newspaper. Archived from the original on 2014-10-18.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  3. "Protests over UNILAG name change persist". Daily Independent, Nigerian Newspaper. Archived from the original on 2014-10-18.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  4. "Displaying items by tag: university of lagos". Campus Daily Online. Archived from the original on 2014-10-22. Retrieved 2024-02-08. 
  5. "UNILAG VC, Prof. Tokunbo Sofoluwe, dies after heart attack". The Punch - Nigeria's Most Widely Read Newspaper. Archived from the original on 2014-10-17.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  6. "UNILAG names Bello as Acting Vice Chancellor - www.channelstv.com". Channels Television. 
  7. "Tributes as UNILAG VC Slumps, Dies at 62, Articles - THISDAY LIVE". Archived from the original on 2014-10-16.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  8. "Prof. Bello appointed substantive VC for UNILAG « The Eagle Online - The Nigerian Online Newspaper". 
  9. "UNILAG holds first Investiture ceremony for 11th VC". 
  10. "Admission to varsities not based on discretion, says ex- VC" (in en-US). https://guardian.ng/news/admission-to-varsities-not-based-on-discretion-says-ex-vc/.