Erékùṣù Robben
Erékùṣù Robben Robben Island* | |
---|---|
Ibi Ọ̀ṣọ́ Àgbáyé UNESCO | |
Prison buildings on Robben Island. Table Mountain is visible 15 km in the background | |
State Party | ![]() |
Type | Cultural |
Criteria | iii, vi |
Reference | 916 |
Region** | Africa |
Coordinates | 33°48′24″S 18°21′58″E / 33.806734°S 18.366222°ECoordinates: 33°48′24″S 18°21′58″E / 33.806734°S 18.366222°E |
Inscription history | |
Inscription | 1999 (23rd Session) |
* Name as inscribed on World Heritage List. ** Region as classified by UNESCO. |
Erékùṣù Robben (Geesi: Robben Island; Afrikaans Robbeneiland) jẹ́ erékùṣù ní Table Bay, tí ó jẹ́ kìlómítà méje lẹ́bàá Cape Town, ní Gúúsù Áfíríkà. Ó jẹ́ èdè Dọ́tsh fún "seal island". Erékùṣù Robben rí bíi oval, 3.3 km gígùn láti àríwá dé gúúsù, àti 1.9 km ní fífẹ̀, pẹ̀lú ààlà tó jẹ́ 5.07 km².[1] Pẹlẹbẹ ni, ó sì jé bíi mítà mélòó sókè ìpele omi-òkun, nítorí agbára-omi tó ṣẹlẹ̀ nígbà ijọ́un. Ó kún fún àwọn okuta ateyinda igba Atetesi Kambria nínú Adipo Malmesbury Group. Erékùṣù yìí ṣe pàtàkì nítorí pé ibẹ̀ ni Ààrẹ ilẹ̀ Gúúsù Áfíríkà ọjọ́ iwájú àti ẹ̀bùn Nobel Nelson Mandela àti Ààrẹ ilẹ̀ Gúúsù Áfíríkà ọjọ́ iwájú Kgalema Motlanthe,[2] bakanna mo awon elewon oloselu miran, ti lo igba ewon won ni asiko apartheid. Jacob Zuma to je Aare ile Guusu Afrika tẹlẹ na lo odun mewa nibe bi elewon.
![]() |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "?".
- ↑ "New S. Africa president sworn in". BBC News. 2008-09-25. Retrieved 2008-11-22.