Roti (fiimu 2017)
Ìrísí
Roti | |
---|---|
Adarí | Kunle Afolayan |
Òǹkọ̀wé | [Shola Dada] |
Àwọn òṣèré | Kate Henshaw Fathia Balogun |
Déètì àgbéjáde |
|
Orílẹ̀-èdè | Nigeria |
[[
Roti jẹ fiimu Naijiria ti ọdun 2017 ti Kunle Afolayan kọ ati se oludari re.
Àkọlé àwòrán
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ọkọ àti aya kan tó ń jẹ́ Diane àti Kabir pàdánù ọmọkùnrin wọn tó jẹ́ ọmọ ọdún mẹ́wàá tó ń jé́ Roti nítorí àrùn ọkàn. Iku roti je ohun ibanuje fun Diane ti o jẹ iya re.
Àwọn tó ń ṣe kopa
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Kate Henshaw
- Kunle Afolayan
- Toyin Oshinaike
- Fathia Balogun
- Darimisiri Afolayan