Jump to content

Samuel obi

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Sam Obi
Member representing Ika North East constituency in Delta State house of assembly
In office
2003–2015
10th Speaker of Delta State house of assembly
In office
29 July 2010 – 7 June 2011
AsíwájúMartin Okonta
Arọ́pòVictor Ochei
Governor of Delta State
In office
10 November 2010 – 10 January 2011
AsíwájúEmmanuel Uduaghan
Arọ́pòEmmanuel Uduaghan
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí
Samuel Onyeka Obi

Àdàkọ:Birth based on age as of date
Aláìsí (ọmọ ọdún 59)
Asaba, Delta State, Nigeria
Cause of deathUndisclosed illness
Ọmọorílẹ̀-èdèNigerian
Occupation
  • Politician
  • pastor

Samuel Onyeka Obi (1961/2 – ọjọ́ kẹta oṣù kẹrin ọdún 2020) jẹ́ olóṣèlú àti òṣeré ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà nígbà ayé rẹ̀. Òun ni asọ̀rọ̀ fún ilé ìgbìmọ̀ asofin Ìpínlẹ̀ Delta, òun sì ni ó di ipò gomina Ìpínlẹ̀ Delta mú láàrin ọdún 2010 sí 2011. Títí di ìgbà ikú rẹ̀, òun ni olùṣọ́ àgùntàn àgbà ti ìjọ Oracle of God Ministry, Asaba, Ìpínlẹ̀ Delta.

Obi wá láti Ibiegwa quarters, Ute-Okpu, Ika North East, Ìpínlẹ̀ Delta, Nàìjíríà. Ó jẹ́ ọmọ ọba àti ọmọ ìdílé Ute-Okpu royal family. Ẹ̀gbọ́n rẹ̀, HRM Obi Solomon Chukwuka I ni Obi ìlú Ute-Okpu lọ́wọ́ lọ́wọ́.[1]

Obi fi ayé sílẹ̀ ní ilé rẹ̀ ní ìlú Asaba ní ọjọ́ kẹta oṣù kẹrin ọdún 2021, èyí ṣẹlẹ̀ lẹ́yìn àìsàn rán pé tí ó ṣe.[2]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Ute-Okpu monarch expresses concern over youths' lack of respect for elders". The Nation Newspaper. 10 April 2015. Retrieved 7 April 2021. 
  2. Odunsi, Wale (4 April 2021). "Sam Obi, ex-Delta acting governor is dead". Daily Post Nigeria. https://dailypost.ng/2021/04/04/sam-obi-ex-delta-acting-governor-is-dead.