Silverbird Galleria

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Silverbird Galleria jẹ́ ilé-ìtàjà àti ààyè fún eré-ìdárayá ní Victoria Island, Lagos.[1]

Ìtàn[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n ṣe ìdásílẹ̀ Silverbird Galleria ní ọdún 2004, láti ọwọ́ ẹgbẹ́ Silverbird,[2] tí í ṣe ilé-iṣẹ́ ìgbéròyìnjáde àti òǹtàjà ilé àti ilẹ̀ tí Ben Murray-Bruce ṣe ìdásílẹ̀ rẹ̀ ní ọdún 1980. Ilé ìwò fíìmù náà, Silverbird Cinema tí ó mú ìyípadà bá ètò sinimá ní Nàìjíríà[3] tí ó sì jẹ́ aṣáájú fún àwọn ìwò ní ilẹ̀ Africa. Sinimá yìí tún ní ẹ̀ka lóríṣiríṣi ní Lagos, Abuja, Port Harcourt, Uyo àti Accra, Ghana.

The Lagos Galleria[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Cinema

Àwọn ìtọ́ka sí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

External links[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àdàkọ:Shopping malls in Nigeria Àdàkọ:Lagos