Stan Nze
Stan Nze | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Stanley Ebuka Nzediegwu 15 Oṣù Kàrún 1989 |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Nnamdi Azikiwe University |
Iṣẹ́ | Actor |
Ìgbà iṣẹ́ | 2009 - present |
Gbajúmọ̀ fún | Rattlesnake: The Ahanna Story |
Awards | AMVCA Best Actor in a Drama |
Stanley Ebuka Nzediegwu (tí wọ́n bí ní ọjọ́ karùndínlógún oṣù Karùn-ún ọdún 1989) tí ọ̀pọ̀ ènìyàn mọ̀ sí Stan Nze jé òṣèrékùnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ó gbajúmọ̀ fún ìkópa rẹ̀ nínú fíìmù Rattlesnake.[1] Stan gba àmì-ẹ̀yẹ AMVCA fún fíìmù yìí ní ọdún 2022, gẹ́gẹ́ bí òṣèrékùnrin tó dára jù lọ.[2]
Ìgbésí ayé rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Stan Nze gba oyè ẹ̀kọ́ nínú ìmọ̀ Computer Science ní Yunifásítì Nnamdi Azikiwe ní Awka.[3] Ó tún kẹ́kọ̀ọ́ nípa eré-ṣíṣe ní Stella Damasus Arts Foundation.[1]
Ìṣàfihàn àkọ́kọ́ rẹ̀ wáyé ní ọdún 2009, nínú fíìmù Private Sector, lẹ́yìn náà ni ó kópa nínú fíìmù Murder At Prime Suites tó jáde ní ọdún 2013, tí ó ti ṣe ẹ̀dá-ìtàn apànìyàn alárùn ọpọlọ.[1]
Ó gbé arábìnrin Blessing Jessica Obasi níyàwó ní ọjọ́ kọkànlá oṣụ̀ kẹsàn-án ọdún 2021, ní ìlú Èkó.[1]
Àtòjọ àwọn fíìmù rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àwọn fíìmù àgbéléwò
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ọdún | Àkọ́lé | Ipa | Àkọsílẹ̀ | Ìtọ́ka |
---|---|---|---|---|
Ọdún 2013 | Murder at Prime Suites | Adolf | First film role | |
Ọdún 2015 | Bad Drop | O tun ṣe iranṣẹ bi olupilẹṣẹ | [4] | |
Ọdún 2016 | Just not married | Duke Nyamma | [5] | |
2017 | Omoye | Peter | [6] | |
2020 | Rattlesnake: Itan Ahanna | Ahanna | [7] | |
2021 | Prophetess | Buntus | [8] | |
Bitter Rain | Ebuka | [9] | ||
Charge and Bail | Dotun | [10] | ||
2021 | Aki and Pawpaw | [11] | ||
2022 | Hey You (fiimu 2022) |
Àwọn ètò orí ẹ̀rọ-amóhùnmáwòrán
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ọdún | Àkọ́lé | Ipa | Àkọsílẹ̀ | Ìtọ́ka |
---|---|---|---|---|
2009 | Private Sector | [1] | ||
Tinsel | Ohakanu | [12] | ||
2016-17 | This Is It | Sam | [13] |
Àmì-ẹ̀yẹ àti yíyàn fún àmì-ẹ̀yẹ
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ọdún | Àmì-ẹ̀yẹ | Ìsọ̀rí | Iṣẹ́ | Èsì | Ìtọ́ka |
---|---|---|---|---|---|
2016 | Zulu African Film Academy Awards (ZAFAA) | Best Lead Actor | Just Not Married | Wọ́n pèé | [14] |
2019 | Best of Nollywood Awards | Best Supporting Actor –English | Thick Skinned | Wọ́n pèé | [15] |
2020 | Best of Nollywood Awards | Best Actor in a Lead role –Igbo | Ishi Anyaocha | Wọ́n pèé | [16] |
2021 | City People Movie Awards | Best Actor | Rattlesnake: The Ahanna Story | Gbàá | [17] |
Best of Nollywood Awards | Gbàá | [18] | |||
Best Kiss in a Movie | Yàán | [19] | |||
2022 | Africa Magic Viewers' Choice Awards | Best Actor in A Drama | Gbàá | [19] |
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ 1.0 1.1 1.2 1.3 1.4 "Two popular Nollywood stars don marry each oda" (in Nigerian Pidgin). https://www.bbc.com/pidgin/world-58535059. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; name ":0" defined multiple times with different content - ↑ "Stan Nze, Osas Ighodaro win big - Full list of all di winners from 2022 AMVCA". BBC News Pidgin (in Nigerian Pidgin). 2022-05-14. Retrieved 2022-07-26.
- ↑ Oguntayo, Femi (2021-01-30). "9 showbiz stars to watch out for in 2021". Tribune Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-11-14.
- ↑ "Must watch movie of the year to be premiered this June". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2015-06-19. Retrieved 2021-09-17.
- ↑ "Meet cast in new character posters". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2016-04-27. Retrieved 2021-09-17.
- ↑ "Tina Mba, Stan Nze, others return in 'Omoye'". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2017-10-20. Retrieved 2021-09-17.
- ↑ "Osas Ighodaro, Efa Iwara, Stan Nze to star in 'Rattle Snake' remake directed by Ramsey Nouah". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-09-02. Retrieved 2020-12-22.
- ↑ "Niyi Akinmolayan's Mighty Prophetess". THISDAYLIVE (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-04-03. Retrieved 2021-09-17.
- ↑ "Watch the official trailer for 'Bitter Rain'". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-08-05. Retrieved 2021-09-17.
- ↑ "INKBLOT production releases trailer for high anticipated blockbuster, charge and bail". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-09-16. Retrieved 2021-09-16.
- ↑ "'Aki and Pawpaw' remake rakes in N30 million in first week – P.M. News" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-07-29.
- ↑ "17 actors you may have forgotten were on "Tinsel"". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2017-05-16. Retrieved 2021-09-17.
- ↑ "Top 5 TV and web series of the year". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2017-12-12. Retrieved 2021-09-17.
- ↑ "ZAFAA 2016: Ini Edo, Eniola Badmus, Stan Nze and more make nomination list". Nigerian Entertainment Today (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2016-11-29. Retrieved 2021-09-17.
- ↑ Bada, Gbenga (2019-12-15). "BON Awards 2019: 'Gold Statue', Gabriel Afolayan win big at 11th edition". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-10-10.
- ↑ Augoye, Jayne (2020-12-02). "2020 BON: Here are 5 nominees for 'Best Kiss' category" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-10-11.
- ↑ "OLAIDE ALMAROOF, ANIKE AMI, STAN NZE, others win in grand style at the 2021 City People Movies Award". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-08-31. Retrieved 2021-09-17.
- ↑ "BBNaija Pere bags 'Best Actor' nomination in 2021 BON Awards". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-09-11. Retrieved 2021-09-17.
- ↑ 19.0 19.1 Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedAMVCA