Tóbi Oyinlolá
Tóbi Oyinlolá | |
---|---|
Tóbi Oyinlolá ni Intel Jẹ́mánì | |
Ìbí | Tóbi Oyinlolá 10 Oṣù Kàrún 1992 Ìbàdàn |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Nàìjíríà |
Ibi ẹ̀kọ́ | Tai Solarin University of Education |
Tóbi oyinlolá (ojó ìbí:ojó kewàá osù Kaàrún odún 1992 ni ilú ìbàdàn,Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ Nàìjíríà)
Omo bíbí orílè èdè Nàìjíríà tí ó jé onísòwò àti òjògbón. Ó lààmìlaaka lénu isé rè pèlú ilé-isé rloop incorporated, ilé-isé tí ó n gbìmò pò láti rii dájú pé àlá ìlanà ìrin àjò oní ìpele kaàrún ti Elon Musk se agbáterù rè wà sí ìmuse.[1] [2]
Tóbi Oyinlolá ni ó se agbáterù èro ònkà ìgbàlódé tí ó ma fún wa láàye láti San owó gáàsì ìdáná bí a sé n lòó. Èyí máa se àrídájú wípé àwon asàmúlò gáàsì ìdáná kò ní láti San owó gboboi lóríi gáàsì lékàn-an náà,tí ó sì jé pé owó ìwònba tí wón bá lò ni wón yíò San.[3]
Ògbéni Olúwatóbi se agbáterù irinsé tó dá sisé,pèlú ìtònsán Òrùn(Solar energy)fún ijó méta pèlú àjòsepò ìlú Kòréà Gúúsù,Amẹ́ríkà,àti Índíà.[4]
Ní Odún 2018,Wón dárúko rè pèlú àwon òdó mìíràn pèlú Davido gégébí àwon tí ó wúlò fún àwùjo.[5]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Oluwatobi Oyinlola". aficta.africa. Retrieved 20 November 2019.
- ↑ "rLoop is the Latest Team Hellbent on Making Hyperloop a Reality". Autoevolution. Retrieved 20 November 2019.
- ↑ "Pay-as-you-cook technology to boost use of affordable LPG in Rwanda". CNBCAfrica (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 28 April 2019. Retrieved 16 September 2019.
- ↑ "Nigerian Tech Genius". Face2faceafrica (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 20 November 2019.
- ↑ "Most Influential Award". Pulse.NG. Retrieved 20 November 2019.