Jump to content

Temilade Openiyi

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Temilade Ọpeniyi ni wọ́n bí ní ọjọ́ kọkànlá oṣù kẹfà ọdún 1995. Orúkọ tí àwọn ènìyàn mọ̀ ọ́ sí jùlọ ni Tems.[1] Ó jẹ́ akọrin ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà, oǹkọ̀wé orin àti o ǹṣe àwo orin.

Tems
Ọjọ́ìbíTemilade Openiyi[2]
11 Oṣù Kẹfà 1995 (1995-06-11) (ọmọ ọdún 29)
Lagos, Nigeria
Iṣẹ́
 • Singer
Ìgbà iṣẹ́2018 - present
Musical career
Irú orin
InstrumentsVocals
LabelsLeading Vibe LTD
Associated acts

Ìbẹ̀rẹ̀ ayé e rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Temilade Ọpeniyi ni wọ́n bí ní ọjọ́ kọkànlá oṣù kẹfà ọdún 1995 ní Ipinle Eko, orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ìyá rẹ jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà nígbà tí bàbá rẹ jẹ́ ọmọ ilẹ̀ gẹ̀ẹ́sì. Lẹ́yìn ìgbà tí wọ́n bí Tems ni àwọn ẹbí rẹ lọ sí orílẹ̀-èdè gẹ̀ẹ́sì. Nígbà tí Tems pé ọmọ ọdún márùn ún ni ìyá àti bàbá rẹ pínyà. Ó padà sí l̀lúpéjú kí ó tó di wípé ó wá lọ sí Lẹkki lẹ́yìn naa Àjáh.[3] Nígbà tí Tems wà ní ilé-ẹ̀kọ́ ni olùkọ́ rẹ tí ó ńkọ ní ẹ̀kọ́ orin ti kọ́kọ́ ṣe àkíyèsi rẹ. Tems kọ́ nípa dùrù títẹ̀, ó sì tún kọ́ orin kíkọ pẹ̀lú gìtá ẹ̀gbọ́n rẹ.[4]

Iṣẹ[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ní ọdún 2018 ó ṣe ìgbàsílẹ̀ àkójọpọ̀ orin tirẹ̀ tí ó pè ní Mr Rebel.[5] Ní oṣù kẹjọ ọdún 2019, Tems ṣe àgbéjáde àwo orin kan, Gbiyanju Me.[6] Eléyì í di ìlúmọ̀ọ́ká tí ó fi jẹ́ wípé àwọn ènìyàn tí wọ́n ń wò ó lori ẹ̀rọ ayélujára ti YouTube lọ́wọ́lọ́wọ́ báyì í ju miliọnu 5.6 lọ. Ní ọdún 2020, DJ Edu yàn án gẹ́gẹ́ bí i ọ̀kan nínú “àwọn òṣèré mẹ́wàá tí òun yí ò wò” ní ọdún na.[7] Ní ọdún kanna yí ni akọrin ọmọ ilẹ̀ Améríkà tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Khalid gbà á láti darapọ̀ mọ́ òun àti Davido ẹlẹgbẹ́ rẹ tí í ṣe ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà lórí Afrobeats remix ti Mọ Iye Rẹ̀.[8] Iṣẹ́ rẹ tí ó pè ní "single Damages from her For Broken Ears EP di ìlú mọ̀ ọ́ ká òmíràn lẹ́yìn "single Try Me" tí ó ṣe. Orin yi ni ó wà ní ipele kẹfà lórí ìgbékalẹ̀ tuntun ti "Turn Table Top 50" (ìwé àpẹrẹ ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà kan) àti wípé àwọn tí wọ́n ǹ wó ó lórí ẹ̀rọ ayélujára ti YouTube tó miliọnu 2.7. Ní ọdún 2020, ìfọwọ́sowọ́pọ̀ rẹ pẹ̀lú Wizkid lórí orin wọn, Essence jẹ́ kí ó wà ní ìpele ìkínní lórí BBC 1Xtra Airplay Chart[9] láti bí í ọgbọ̀n ọjọ́ oṣù kínní ọdún 2021.[10]

Ní oṣù Kejìlá ọdún 2020, Tems àti òṣèré ẹlẹgbẹ́ rẹ tí ó tún jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Omah Lay ni wọ́n mú ní orílẹ̀-èdè Uganda, ní àkókò tí wọ́n lọ síbẹ̀ fún iṣẹ́ orin kíkọ, fún ẹ̀sùn pé wọn kò tẹ̀lé àwọn òfin tí ó rọ̀ mọ́ ààbò lórí àrùn COVID-19. Lẹ́hìn na ni wọ́n tú wọn sílẹ̀ tí wọ́n sì fagilé gbogbo ẹ̀sùn tí wọ́n fi kàn wọ́n.[11]

Àwòrán ìwòye[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn kékèèké[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ọdún Àkọlé Àwọn àwo-orin
2018 "Mr Rebel"[12] Non-album single
2019 "Looku Looku"[13]
"Try Me"
2020 "These Days"[14]
"Damages" For Broken Ears

EPs[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àkójọ àwọn eré tí ó gbòòrò sii, àti ìwé-ẹ̀rí.
Àkọlé Àwọn àlàyé àwo-orin Ìwé-ẹ̀rí
For Broken Ears
 • Released: September 25, 2020 (NG)
 • Label: Leading Vibes LTD
 • Formats: digital download, streaming

Àwọn ẹ̀bùn àti àwọn yíyàn[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ọdún Ìṣẹ̀lẹ̀ Ẹ̀bùn Olùgba ẹ̀bùn Èsì Ref
2019 The Headies Best Vocal Performance (Female) "Mr Rebel" Wọ́n pèé [15]
Best Alternative Song Wọ́n pèé
2020 The Headies Next Rated "Omah Lay" Wọ́n pèé [16]
The Future Awards Africa Prize for Music Wọ́n pèé [17]
2021 BET Awards Best New International Act Wọ́n pèé [18][19]
MTV Africa Music Award Best Breakthrough Act Iṣẹ́ ń lọ lórí ẹ̀ [20]
Net Honours Most Played Alternative Song "Damages" Gbàá [21]
All Africa Music Awards Best Female Artist in Western Africa Herself Wọ́n pèé [22][23][24]
Best African Collaboration "Essence"

(Wizkid featuring Tems)

Gbàá
Song of the Year Gbàá
Best Artist, Duo or Group in African RnB & Soul Wọ́n pèé
"Damages" Wọ́n pèé
Breakout Artist of the Year Herself Wọ́n pèé
African Entertainment Awards USA Best Female Artist Gbàá [25]
Artist of the Year Wọ́n pèé
Best Female Artist – Central/West Africa Wọ́n pèé
Best Collaboration "Essence"

(Wizkid featuring Tems)

Gbàá
Best Video Gbàá
Song of the Year Gbàá
MTV Europe Music Awards Best African Act Herself Wọ́n pèé [26]
Soul Train Music Awards Best Collaboration "Essence"

(Wizkid featuring Tems)

Gbàá [27]
Video of the Year Wọ́n pèé
Song of the Year Wọ́n pèé
The Ashford & Simpson Songwriter's Award Wọ́n pèé
Best New Artist Herself Wọ́n pèé
Afro X Digitals Awards Pop Song of the Year (Female) "Damages" Àdàkọ:Win [28]
The Beatz Awards Songwriter of the Year Herself for "Damages" Wọ́n pèé
2022 Grammy Awards Best Global Music Performance "Essence"

(Wizkid featuring Tems)

Wọ́n pèé [29][30]
NAACP Image Awards Outstanding New Artist Herself Wọ́n pèé [31]
Outstanding Music Video/Visual Album "Essence"

(Wizkid featuring Tems)

Gbàá
Outstanding International Song Gbàá
Nickelodeon Kids Choice Award Favorite Global Music Star Herself Wọ́n pèé [32]
The Headies Best Vocal Performance (Female) Herself for "Essence" Iṣẹ́ ń lọ lórí ẹ̀ [33]
Best Collaboration "Essence"

(Wizkid featuring Tems)

Iṣẹ́ ń lọ lórí ẹ̀
Best R&B Album w:If Orange Was a Place Iṣẹ́ ń lọ lórí ẹ̀
Best Female Artiste Herself Iṣẹ́ ń lọ lórí ẹ̀
BET Awards Best New Artist Wọ́n pèé [34][35][36]
Best International Act Gbàá
Best Collaboration "Essence"

(Wizkid featuring Tems)

Gbàá

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

 1. Tariemi, Oreoritse (May 9, 2022). "Tems Becomes First Nigerian Artist To Debut No. 1 On Billboard Hot 100". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News. Archived from the original on May 16, 2022. Retrieved May 29, 2022. 
 2. "Singer Tems". Daily Trust. April 2, 2022. Retrieved May 29, 2022. 
 3. Laketu, Adedayo (2020-03-09). "The sweet, arresting harmonies of Nigeria’s Tems". The FADER. Retrieved 2021-04-16. 
 4. Okare, Fisayo (2018-10-23). "Native Exclusive: How Tems Triumphs after "Mr Rebel"". The Native. Retrieved 2021-04-16. 
 5. Okare, Fisayo (2018-10-23). "Native Exclusive: How Tems Triumphs after "Mr Rebel"". The Native. Retrieved 2021-04-16. 
 6. Obi, Ify (2020-02-06). "Interview: Tems Is On a Mission to Take Over". OkayAfrica. Retrieved 2021-04-16. 
 7. "Rema". OkayAfrica. 2020-02-06. Retrieved 2021-04-16. 
 8. Samanga, Rufaro (2020-04-23). "Khalid Recruits Davido and Tems on New Single 'Know Your Worth (Remix)'". OkayAfrica. Retrieved 2021-04-16. 
 9. "BBC 1Xtra Airplay Chart". The UK Radio Airplay Chart. Archived from the original on 2021-01-20. Retrieved 2021-04-16. 
 10. "The Essence of Wizkid and Tems". Mp3Chord. 2021-04-10. Retrieved 2021-04-16. 
 11. "BebeCool: Tems accuse Uganda musician of making police arrest her and Omah Lay". BBC News Pidgin. 2020-12-19. Retrieved 2021-04-16. 
 12. "Burna Boy, Davido, Teni, others get nominated for 2019 Headies [FULL LIST]". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-02-12. 
 13. "Lady Donli 'Corner' feat. VanJess & The Cavemen". OkayAfrica (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-12-12. Retrieved 2020-02-12. 
 14. "Tems - These Days". Notjustok (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-05-19. Archived from the original on 2020-06-14. Retrieved 2020-05-21. 
 15. "Headies 2019: Here are all the winners at the 13th edition of music award". Pulse Nigeria. 20 October 2019. Retrieved 26 October 2019. 
 16. "Live Update: All The Winners At The Headies 2020". The Guardian. 2021-02-21. Retrieved 2021-02-25. 
 17. Obi-Young, Otosirieze (9 November 2020). "The Future Awards Africa 2020 Announces 145 Nominees in 20 Categories". Folio. Retrieved 16 June 2021. 
 18. "2021 BET Awards: Full list of winners and nominees". CBS News. Retrieved 29 June 2021. 
 19. Unamaka, Sampson (8 June 2021). "Nigerian singer Tems clinches 2021 BET Awards nomination". The Nation (Nigeria). Retrieved 9 June 2021. 
 20. "See the Full List of 2021 #MTVMAMA Nominees including Tems, Omah Lay and Rema!". BellaNaija. 9 December 2020. Retrieved 16 June 2021. 
 21. Mofijesusewa, Samuel (20 June 2021). "NET Honours 2021: "Damages" by Tems Named Most Played Alternative Song". Nigerian Entertainment Today (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 21 July 2021. 
 22. "All Africa Music Awards 2021: All the nominees". Music in Africa (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 23 September 2021. Retrieved 27 September 2021. 
 23. Obey, Yinka (25 November 2021). "AFRIMA 2021: Wizkid, Iba One win big, Manjeru makes history, full list of winner". Legit.ng – Nigeria news. (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-11-26. 
 24. "2021 AFRIMA Awards – See Full Winners List". tooXclusive (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 22 November 2021. Retrieved 2021-11-26. 
 25. "Wizkid wins five awards at 2021 AEAUSA". The Nation Newspaper. 28 December 2021. Retrieved 28 December 2021. 
 26. "Wizkid Wins Best African Act At MTV EMA 2021". The Guardian Nigeria News – Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 15 November 2021. Archived from the original on 2021-11-23. Retrieved 2021-11-23. 
 27. "H.E.R. Is Top Nominee at 2021 Soul Train Awards; Maxwell & Ashanti to Receive Special Awards: Exclusive". Billboard. Retrieved 2 November 2021. 
 28. "Afrodigital Award winners". AfroxDigital.com. 
 29. "Wizkid, Burnaboy, oda Nigerian artists wey dey 2022 Grammy nomination". BBC News Pidgin. https://www.bbc.com/pidgin/media-59394925. 
 30. "2022 Grammy Awards: Wizkid, Femi Kuti, Burna Boy, Tems nominated". Vanguard News. 3 April 2022. Retrieved 4 April 2022. 
 31. Spivey, Kemberlie (19 January 2022). "2022 NAACP Image Awards Nominations: The Full List". Forbes (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-01-20. 
 32. "Kids' Choice Awards Nominees: See Who's Up for Favorite Actor, Actress and Movie | Entertainment Tonight". www.etonline.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-05-07. 
 33. "2022 Headies Full List Nominees". Vanguard News. 24 May 2022. Retrieved 25 May 2022. 
 34. "BET Awards 2022 Nominees Announced". BET (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2 June 2022. 
 35. "Tems wins Best International Act at BET Awards 2022". Vanguard News. June 27, 2022. Retrieved June 27, 2022. 
 36. "BET Awards: Tems wins 2022 Best International Act". Punch Newspapers. June 27, 2022. Retrieved June 27, 2022.