The Campus Queen

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
The Campus Queen
AdaríTunde Kelani
Òǹkọ̀wéAkínwùmí Iṣọ̀lá
Àwọn òṣèré
OrinSound Sultan
Ìyàwòrán sinimáTunde Kelani
OlùpínRolex Nigeria Limited
Déètì àgbéjáde
  • Oṣù Kẹrin 2004 (2004-04) (Nigeria)
Àkókò100min
Orílẹ̀-èdèNigeria
ÈdèYoruba and English

The Campus Queen jẹ́ fíìmù ilẹ̀ Nàìjíríà ti ọdún 2004, èyí tí Tunde Kelani darí, pẹ̀lú Mainframe Films and Television Productions tí wọ́n ṣe àgbéjáde fíìmù náà.[1][2] Ìṣàfihàn àkọ́kọ́ fíìmù yìí wáyé ní African Film Festival, ní New York City, U.S.A, ní ọdún 2004. Òun sì ni wọ́n yàn ní Black Film Festival ní Cameroon.[3]

Ìpilẹ̀ṣẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

The Campus Queen jẹ́ fíìmù olórin, ijó àti oríṣiríṣi ìṣe àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ní ilé-ẹ̀kọ́ gíga. Ó sì tún yànnàná ìfẹ́ àwọn akẹ́kọ̀ọ́ fún ipò àti ṣíṣe àkóso.[4]

Àwọn akópa[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "7 Tunde Kelani Films You Should Watch Immediately". 9 September 2015. Retrieved 16 September 2015. 
  2. Ayodele Lawal; Femi Adepoju (10 October 2003). "Nigeria: Kelani Rolls Out 'Campus Queen', Sound Sultan Gets a Role". P.M. News (All Africa). http://www.allafrica.com/stories/200310100440.html. Retrieved 16 September 2015. 
  3. "The Campus Queen Premiers". Thisday Live. 12 June 2004. http://www.naijarules.com/index.php?threads/the-campus-queen-premieres.2715/. Retrieved 16 September 2015. 
  4. "Campus Queen". 10 November 2011. Archived from the original on 19 April 2015. Retrieved 16 September 2015.