Jump to content

Afárá Third Mainland

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Third Mainland Bridge)
Afara Third mainland ni ale
Third Mainland Bridge
Carries Vehicular Traffic
Crosses Lagos Lagoon
Locale Lagos, Nigeria
Toll No
Third Mainland bridge

Afárá Third Mainland tabi Third Mainland Bridge ni o gunjulo ninu awon afara meta to sejapo Erekusu Eko, Lagos, Nigeria mo oluile, awon meji to ku ni afara Eko ati Carter. Ohun ni afara to gunjulo ni Africa. Afara Third Mainland bere lati Oworonshoki to jamo ojuona Apapa-Oshodi ati ojuona Lagos-Ibadan, o si dopin ni iyana Adeniji Adele ni Lagos Island. Ile-ise Julius Berger Nigeria PLC lo ko ni 1990 labe ijoba ologun Aare Ibrahim Babangida. Igun re je 11.8km.


Awon alaje ni ori afara third mainland


Coordinates: 6°30′00″N 3°24′05″E / 6.50000°N 3.40139°E / 6.50000; 3.40139