Jump to content

Vicente Aleixandre

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Vicente Aleixandre

Ojo ibi Vicente Aleixandre je ojo kerindinlogbon, osu igbe ni odun 1898 ni ilu sevilla ni orile ede Spain,o je omo fun onimo ero oko oju irin. O je akeko to gboye imo ijinle nipa ofin ati eeto nipa oro aje ni odun 1919 , laarin odun 1920 si odun 1922 O sise oluko ni ile iwe ti won ti nko nipa ofin to ro mo owo sise. O se aisan to lagbara die ti a npe ni iko ife[TUBERCULOSIS] ni odun 1925.O yan ise iwe kiko yii ni aayo ni odun 1926, O je okan pataki lara awon omo egbe olukowe ilu Spain ni tile toko ni odun 1927, ni akoko to nse aisan yii lo ko ewi [POEM] re akoko ti akole re je [AMBITO] ti o si jade ni odun 1928. O wa ni orile ede Spain lasiko ogun abele Spanish. Lotito won gbese le iwe ewi ti o ko lati odun 1936 titi di odun 1944. Ni odun 1949 won di ibo yan gege bii olola julo ninu imo ijinle ti ilu Spain. O gba ebun eye ninu litireso ni odun 1977. O je olorun ni ipe ni ojokerinla osu ope ni odun 1984 ni ilu Madrid.