Wọlé Sóyinká

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Wole Soyinka)
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
Wole Soyinka
Ìbí 13 Oṣù Keje 1934 (1934-07-13) (ọmọ ọdún 83)
Abeokuta, Ipinle Ogun, Nigeria
Occupation Author, Poet
Nationality Nigerian
Genres Drama, Poetry
Subjects Comparative literature
Notable award(s) Nobel Prize in Literature
1986

Oluwole Soyinka (ojoibi 13 July 1934) je ojogbon (Professor) ninu Imo Lítíréṣọ̀ (literature), alakosile ere ori itage (playwright) ati akewi (poet). Omo orile ede Naijiria ni Ṣoyinka je, lati eya Yoruba. Soyinka gba Ebun Nobel ni odun 1986 fun ise owo re lori igbega imo ikowe.

Won bi Soyinka ni ilu Abeokuta, Leyin ti o pari eko re ni orile ede Nigeria ati United Kingdom tan, O se ise pelu tiata Royal Court ni ilu Londonu (London). O te siwaju lati ko awon ere ni orile ede mejeeji ni tiata ati ori ero Asoro-magbesi. O ko ipa Pataki ninu itan iselu ati akitiyan lopolopo ninu ijangbara ominira orile-ede Naijiria kuro lowo ijoba amunisin Great Britain.


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]