Wọlé Sóyinká

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
Wole Soyinka
Ìbí 13 Oṣù Keje 1934 (1934-07-13) (ọmọ ọdún 82)
Abeokuta, Ipinle Ogun, Nigeria
Occupation Author, Poet
Nationality Nigerian
Genres Drama, Poetry
Subjects Comparative literature
Notable award(s) Nobel Prize in Literature
1986

Oluwole Soyinka (ojoibi 13 July 1934) je ojogbon (Professor) ninu Imo Lítíréṣọ̀ (literature), alakosile ere ori itage (playwright) ati akewi (poet). Omo orile ede Naijiria ni Ṣoyinka je, lati eya Yoruba. Soyinka gba Ebun Nobel ni odun 1986 fun ise owo re lori igbega imo ikowe.

Won bi Soyinka ni ilu Abeokuta, Leyin ti opa ri eko re ni irile ede Nigeria ati UK, o se ise pelu tiata Royal Court ni ilu Londonu (London). O te siwaju lati ko awon ere ni orile ede mejeeji ni tiata ato ori ero asoro magbesi. O ko ipa Pataki ni itan iselu and akitiyan fun ominira lati owo Great Britain.


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]