T. S. Eliot

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
T. S. Eliot

T. S. Eliot in 1923 by Lady Ottoline Morrell
Ìbí Thomas Stearns Eliot
26 Oṣù Kẹ̀sán, 1888(1888-09-26)
St. Louis, Missouri
Aláìsí 4 Oṣù Kínní, 1965 (ọmọ ọdún 76)
London, England
Occupation Poet, dramatist, literary critic
Ethnicity Caucasian
Citizenship American by birth; British from 1927
Ẹ̀kọ́ A.B. in philosophy
Alma mater Harvard University
Merton College, Oxford
Period 1905–1965
Literary movement Modernism
Notable work(s) The Love Song of J. Alfred Prufrock (1915), The Waste Land (1922)
Notable award(s) Nobel Prize for Literature (1948), Order of Merit (1948)
Spouse(s) Vivienne Haigh-Wood (Vivien) (1915–1947); Esmé Valerie Fletcher (1957 until his death)
Children noneSignature
T S Eliot Simon Fieldhouse.jpg

Thomas Stearns Eliot OM (Ọjọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n Oṣù kẹsán Ọdún 1888 – Ọjọ́ kẹrìn Oṣù kínín Ọdún 1965) jẹ́ akọ-ewì ará Amẹ́ríkà, olùkọ̀wé ere orí-ìtàgé àti olùyẹ̀wò lítíréṣò. Wọ́n gbàá bí ìkan nínú àwọn akọewì pàtàkì ní ogún orundún sẹ́yìn[3] àti ẹni bí aṣíwájú fún ẹgbẹ́ ìrinkankan ìṣe òdeòní nínú ewì. Ní odún 1948 ó gba Ebun Nobel nínú Lítíréṣọ̀. Nínú àwọn isẹ́ owọ́ rẹ̀ ni a ti lè rí Orin ololufe J. Alfred Prufrock (1910), Ile Ahoro (1922), Ese-orin merin (1945)[4] ati ere ori-itage Ipaniyan ninu Soosi (1935)

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Hart Crane (1899-1932)
  2. Influences by Seamus Heaney, Bostonreview.net, accessed August 3, 2009.
  3. Collini, Stefan. I cannot go on, The Guardian, November 7, 2009.
  4. Thomas Stearns Eliot, Encyclopaedia Britannica, accessed November 7, 2009.