William Butler Yeats

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
William Butler Yeats ninu foto ti Alice Boughton ya ni 1903

Williams Butler Yeats (pípè /ˈjeɪts/; 13 June 1865–28 January 1939) je akewi ati onimo ninu Litireso ede Geesi. Omo ile Geesi ni. A bí W.B. Yeats ní 1865. Ó kú ní 1939. Ó ko òpòlopò ewì. O gbà pé nnkan tí ó bá selè ní egbèrún méjì odún kan ni yóò tún selè ní egberún méjì odún tí ó bá tún tèlé é.


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]