Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 13 Oṣù Kọkànlá
Ìrísí
- 1947 – Russia se igbejade ibon AK-47, ibon akoko to je ibon ayinmodaku.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1893 – Edward Adelbert Doisy, onimosayensi ara Amerika (al. 1986)
- 1939 - Idris Mohammad, onilu ati atorin jazz ara Amerika (al. 2014)
- 1955 – Whoopi Goldberg, osere, alawada ati akorin ara Amerika
Àwọn aláìsí lóòní...
- 2004 – Ol' Dirty Bastard, atokun ati olorin rap ara Amerika (ib. 1968)