Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 15 Oṣù Kọkànlá
Ìrísí
- 1971 – Intel releases world's first commercial single-chip microprocessor, the 4004.
- 1990 – Space Shuttle program: Space Shuttle Atlantis launches with flight STS-38.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1889 – Adésọjí Adérẹ̀mí, Ọ̀ọ̀ni Ilé-Ifẹ̀ (al. 1980)
- 1931 – Mwai Kibaki, Ààrẹ ilẹ̀ Kẹ́nyà
- 1968 – Ol' Dirty Bastard, akọrin rap ará Amẹ́ríkà (al. 2004)
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1630 - Johannes Kepler (àwòrán), onimo mathimatiki ati atorawo ara Jemani (ib. 1571).
- 1917 - Émile Durkheim, onimo oro-awujo ara Fransi (ib. 1858).
- 1998 – Kwame Ture, American civil rights activist (ib. 1941)