Adésọjí Adérẹ̀mí

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
Adesoji Tadeniawo Aderemi
Governor of Western Region
Lórí àga
1960–1967
Asíwájú Obafemi Awolowo
Arọ́pò Samuel Ladoke Akintola
Oba of Ife
Lórí àga
1930 – 7 July 1980
Asíwájú Ademiluyi Ajagun
Arọ́pò Okunade Sijuwade
Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́
Ìbí 15 November 1889
Aláìsí 7 July 1980

Adésojí Adérèmí (15 November 18897 July 1980) Oba Nífè Oòni

Oriki[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Emó kú ojú òpó dí. Afèèbòjò kú, enu isà ń sòfò Ekùn ti lo. Oba nÍfè Onòni. Ikú ò meni à á pa, òjò ò meni òwò. Òjò ìbá meni òwò ni, Ìbá tí poníSàngó, Ìbá tí POlóya.

Kááábíyèsí!...

  • S.M. Raji (2003), Igi Ń dá Lektay Publishers, Ibadan, Oju-ìwé 98-101.


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]