Jump to content

Adekunle Fajuyi

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Adekunle Fajuyi
Fáìlì:Fajuyi-Adekunle.JPG
Military Governor of Western Nigeria
In office
15 January 1966 – 29 July 1966
Arọ́pòRobert Adeyinka Adebayo
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí1926
Ado Ekiti, Nigeria
Aláìsí29 July 1966
Ẹgbẹ́ olóṣèlúNone (Military)

Francis Adekunle Fajuyi, BEM (Tí wón bí ní ọjọ́ kẹrìndínlógún oṣù kẹfà ọdún , 1926 - tí ó kú ní ọjọ́ kọkàndínlọ́gbọ̀n oṣù keje ọdún 1966) jẹ́ gómìnà ológun tẹ́lẹ̀ri fún àgbègbè ìwò òòrùn Nàìjíríà ni ayé ìgbàkan Western Region, Nigeria.


Fajuyi fi ìgbà kan je olùkọ́ni àti Akọ̀wé clerk, Fajuyi, ẹni tí ṣe omo ipinle Ado Ekiti, darapọ̀ mọ́ ikò àwọn ọmọ ológun ni Ọdún 1943, gẹgẹbi Sajenti nínú ikò Nigeria Signal Squadron, Royal West African Frontier Force, tí wọ́n sì fún ní àmì Ìdánilólá tí British Empire Medal ní ọdún 1951 lórí akitiyan tí ó ṣe lójúnà áti ṣéwọ́ ìsòtè lori oro oúnjẹ láàrin àwọn akegbé rẹ̀.[1] Wọ́n kò ní ìṣe ológun ní Eaton Hall Officer Candidate School ní orílè èdè United Kingdom bèrè láti ìṣù keje ọdún 1954 titi di osu kọkànlá ọdún 1954, lẹ́yìn tí wọ́n pè sì ìṣe ẹnu ìṣe ológun.[2] Ní ọdún 1961, gẹ́gẹ́bi ọ̀gágun fún ikò 'C' Company pelu ìpín ikò àwọn ọmọ ogun 4 battalion, Queen's Own Nigeria Regiment labẹ Lt. Col. Price, wọ́n fún Major Fajuyi ni àmì ẹ̀yẹ Military Cross fún use takun takun-takun re ni North Katanga àti bí ó ṣe dènà ijamba àwọn ìpín ọmọ ogun labẹ rẹ kúrò lọ́wọ́ ìdènà ijamba àwọn òtá.[3] On completion of Congo, Fajuyi di àkókò Ogagun olùdarí ikò àwọn ọmọ ogun 1st battalion ní Enugu, ipò tí o di mú títí di àkókò ìdìtè gbàjọba coup tí Oṣu Kínní ọdún 1966, kí wọ́n to gbé lọ sí Abeokuta gẹ́gẹ́bi Olórí Búbá Àwọn Ọmọ Ogun. Nígbà tí Ògágun Major General Ironsi di commander in chief ní ọjọ́ kẹtàdínlógún ni Oṣu kinni ọdún 1966, ó yan Fajuyi gẹgẹbi gómìnà ológun àkókò fún àgbègbè ìwò òòrùn Nàìjíríà Western Region.[4]


Wọ́n pa Fajuyi níbi ìkọlù ìdìtè gbajoba láti gba ésàn àwọn tí wọ́n kú níbi ìdìtè gbàjoba àkókò, tí ó ṣe kú pa Major T. Y. Danjuma ní ọjọ́ kọkàndínlọ́gbọ̀n oṣù keje ọdún 1966,[5] ní ìlú Ibadan, pẹ̀lú General Johnson Aguiyi-Ironsi, olórí orile-ede ògá àgbà pátápátá Commander fún àwọn ọmọ ogun orílẹ̀ èdè Olómìnira Nigeria tí wọ́n kale sì ìlú Ìbàdàn ni ọjọ kejìlélógbòn Oṣù keje ọdún 1966 láti bá àwọn àpéjọ Ládé Ládé ìwò òòrùn Nàìjíríà nígbà náà sọ̀rọ̀.[6] Ìdìtè gbàjoba ijoba alagbada tí Alákóso Àgbà orilẹ-ede Naijiria Sir Tafawa Balewa óun lo ṣelè ni nkan bí Oṣu mefa sẹ́yìn níbi tí àwọn olóṣèlú àti èyàn jàǹkàn-jàǹkàn ni apá ilé àríwá tí di olóògbé tí wọ́n bá ìṣẹ̀lẹ̀ ìdìtè gbajoba na lọ.[7]