Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 14 Oṣù Kàrún
Ìrísí
- 1607 – Jamestown, Virginia, Amẹ́ríkà jẹ́ títẹ̀dó gẹ́gẹ́ bíi ibi-àmúsìn Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì.
- 1963 – Kuwait dara pọ̀ mọ́ Àjọ àwọn Orílẹ̀-èdè.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1944 – George Lucas, olùdarí fílmù ará Amẹ́ríkà
- 1961 – Tim Roth, òṣeré ará Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì
- 1966 – Raphael Saadiq, akọrin ará Amẹ́ríkà (ọmọ ẹgbẹ́ olọ́rin Tony! Toni! Toné!)
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1881 – Mary Seacole (àwòrán), ọlùtọ́jú aláìsàn ará Jamáíkà (ib. 1805)
- 1998 – Frank Sinatra, akọrin àti òṣeré ará Amẹ́ríkà (ib. 1915)
- 2015 – B.B. King, akọrin ará Amẹ́ríkà (ib. 1925)