Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 15 Oṣù Kàrún
Ìrísí
Ọjọ́ 15 Oṣù Kàrún: Ọjọ́ Òmìnira ni Paraguay (1811)
- 1991 – Édith Cresson di alákóso àgbà ilẹ̀ Fránsì àkọ́kọ́ tó jẹ́ obìnrin.
- 1997 – Ọkọ̀-àlọbọ̀ Òfurufú Atlantis gbéra lórí STS-84 láti lọ fẹ̀gbẹ́ kan ibi-ìbùdó òfurufú Rọ́síà Mir.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1859 – Pierre Curie, onímọ̀ físíksì ará Fránsì (al. 1906)
- 1915 – Paul Samuelson, onímọ̀ òkòwò ará Amẹ́ríkà (al. 2009)
- 1965 – Raí, agbábọ́ọ̀lù-ẹlẹ́sẹ̀ ará Brasil
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1991 – Amadou Hampâté Bâ, olùkọ̀wé ará Málì (ib. c. 1900)
- 1993 – Salah Ahmed Ibrahim, olùkọ̀wé ará Sudan (ib. 1933)
- 2013 – Henrique Rosa, Ààrẹ ilẹ̀ Guinea-Bissau (ib. 1946)