Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 13 Oṣù Kàrún
Ìrísí
- 1830 – Ecuador gba ìlómìnira látọwọ́ Gran Colombia.
- 1846 – Àwọn Ìpínlẹ̀ Àṣọ̀kan gbé ogun ti Mẹ́ksíkò.
- 1888 – Brasil pa okoẹrú run.
- 1950 – Ìyípo àkọ́kọ́ Ìdíje Àgbáyé Formula One wáyé ní Silverstone.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1914 – Joe Louis, ajẹ̀sẹ́ ará Amẹ́ríkà (al. 1981)
- 1950 – Manning Marable, ọ̀mọ̀wé ará Amẹ́ríkà (al. 2011)
- 1950 – Stevie Wonder (fọ́tò), olórin ará Amẹ́ríkà
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1903 – Apolinario Mabini, Alákóso Àgbà Filipínì (ib. 1864)
- 1938 – Charles Edouard Guillaume, áṣiṣẹ́ẹ̀dá ará Swítsàlandì (ib. 1861)
- 2008 – Saad Al-Abdullah Al-Salim Al-Sabah, Sheikh ilẹ̀ Kùwáìtì (ib. 1930)