Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 17 Oṣù Kàrún
Ìrísí
- 1792 – Ìdásílẹ̀ Ilé Pàṣípàrọ̀ Owó New York.
- 1994 – Malawi ṣe ìdìbòyàn pẹ̀lú ẹgbẹ́ ọ̀ṣèlú púpọ̀ fún ìgbà àkọ́kọ́.
- 1997 – Àwọn ajagun Laurent Kabila wọ Kinshasa. Zaire yí orúkọ ibiṣẹ́ rẹ̀ padà sí Orílẹ̀-èdè Olómìnira Olóṣèlúaráìlú ilẹ̀ Kóngò (Àsìá).
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1936 – Dennis Hopper, òṣeré ará Amẹ́ríkà (al. 2010)
- 1956 – Sugar Ray Leonard, ajẹ̀sẹ́ ará Amẹ́ríkà
- 1966 – Hill Harper, òṣeré ará Amẹ́ríkà
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1987 – Gunnar Myrdal, aṣiṣẹ́òkòwò ará Swídìn (ib. 1898)
- 2007 – T.K. Doraiswamy, olùkọ̀wé ará Índíà (ib. 1921)
- 2012 – Donna Summer, akọrin ará Amẹ́ríkà (ib. 1948)