Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 18 Oṣù Kàrún
Ìrísí
Ọjọ́ 18 Oṣù Kàrún: Ọjọ́ Àsìá ní Hàítì
- 1900 – Orílẹ̀-èdè Ilẹ̀ọba Aṣọ̀kan sọ ilẹ̀ Tonga ibiàbò wọn.
- 2005 – Fọ́tò kejì tí wọ́n yà pẹ̀lú Tẹ́lískópù Òfurufú Hubble fihàn dájúdájú pé Plútò ní òṣùpá méjì míràn: Nix àti Hydra.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1872 – Bertrand Russell, amóye àti aṣiṣéonísirò ará Brítánì (al. 1970)
- 1912 – Walter Sisulu, alákitiyan òṣèlú ará Gúúsù Áfríkà (al. 2003)
- 1923 – Hugh Shearer, Alákósò Àgbà ará Jamáíkà (al. 2004)
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1922 – Charles Louis Alphonse Laveran, oníṣègùn ará Fránsì (ib. 1845)
- 1955 – Mary McLeod Bethune (fọ́tò), olùkọ́ni àti alákitiyan ará Amẹ́ríkà (ib. 1875)
- 2004 – Elvin Jones, onílú jazz ará Amẹ́ríkà (ib. 1927)