Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 15 Oṣù Kẹjọ
Ìrísí
- 1893 - Fijabi, Baálẹ̀ Ìbàdàn fọwọ́bọ̀wé àdéhùn kan pẹ̀lú olùdípò Gómìnà ìlú Èkó ará Brítánì, George C. Denton láti so Ìbàdàn di ibi-àbò Brítánì.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1938 – Maxine Waters, olóṣèlú ará Amẹ́ríkà
- 1973 – Amitabh Bhattacharjee, òṣeré ará Índíà
- 1985 – Nipsey Hussle, olórin rap ará Amẹ́ríkà (al. 2019)
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1953 – Ludwig Prandtl, German physicist (b. 1875)
- 1975 – Sheikh Mujibur Rahman, Bengali politician, 1st President of Bangladesh (b. 1920)
- 1982 – Hugo Theorell, Swedish scientist, Nobel Prize laureate (b. 1903)