Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 20 Oṣù Kẹrin
Ìrísí
- 1871 – Ìṣe àwọn Ẹ̀tọ́ Aráàlú ọdún 1871 di òfin ní Amẹ́ríkà.
- 1902 – Pierre àti Marie Curie ṣe ògidì radium chloride.
- 1972 – Apollo 16 balẹ̀ sí ojú òṣùpá.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1889 – Adolf Hitler, Aláṣẹ ilẹ̀ Germany àwọn Nazi (al. 1945)
- 1920 – Clement Isong, olóṣèlú ará Nàìjíríà (al. 2000)
- 1951 – Luther Vandross, akọrin ará Amẹ́ríkà (al. 2005)
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1887 – Muhammad Sharif Pasha, olóṣèlú ilẹ̀ Egypti (ib. 1826)
- 1932 – Giuseppe Peano, onímọ̀ matimatiiki ara Italia (ib. 1858)
- 2010 – Dorothy Height (foto), alákitiyan ẹ̀tọ́ aráàlú ará Amẹ́ríkà (ib. 1912)