Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 18 Oṣù Kẹrin
Ìrísí
Ọjọ́ 18 Oṣù Kẹrin: Independence Day ni Zimbabwe (Àsìá) (1980).
- 1906 – Ìwàrìrì-ilẹ̀ àti ijona pa San Francisco, California run.
- 1946 – The International Court of Justice holds its inaugural meeting in The Hague, Netherlands.
- 1954 – Gamal Abdal Nasser gba ìjọba ní Egypt.
- 1980 – The Republic of Zimbabwe (formerly Rhodesia) comes into being, with Canaan Banana as the country's first President.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1882 – Ọba Akinyele, Olubadan (al. 1964)
- 1947 – James Woods, American actor
- 1973 – Haile Gebrselassie, Ethiopian athlete
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1955 – Albert Einstein, German physicist (b. 1879)
- 1995 – Arturo Frondizi, President of Argentina (b. 1908)
- 2011 – Olubayo Adefemi, Nigerian footballer (b. 1985)