Arturo Frondizi
Appearance
Arturo Frondizi | |
---|---|
arẹ orílè-èdè Argentina | |
In office May 1, 1958 – March 29, 1962 | |
Vice President | Alejandro Gómez (May–Nov 1958) None (1958–1962) |
Asíwájú | Pedro Eugenio Aramburu |
Arọ́pò | José María Guido |
National Deputy | |
In office June 4, 1946 – June 4, 1952 | |
Constituency | Buenos Aires |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Arturo Frondizi Ércoli October 28, 1908 Paso de los Libres, Corrientes, Argentina |
Aláìsí | April 18, 1995 Buenos Aires, Argentina | (ọmọ ọdún 86)
Resting place | Basílica de la Inmaculada Concepción, Entre Ríos, Argentina |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Argentine |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Radical Civic Union (1932–1956) Intransigent Radical Civic Union (1956–1963) Integration and Development Movement(1963–1986) |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Elena Luisa María Faggionato (m. 1933; died 1991) |
Àwọn ọmọ | Elena Frondizi Faggionato |
Alma mater | University of Buenos Aires |
Profession | agbẹ́jọ̀ro |
Signature |
Arturo Frondizi je Aare orile-ede Argentina tele.
Arturo Frondizi Ércoli (October 28, 1908 – April 18, 1995) jẹ́ agbẹjọro, oniroyin,olùkó, olóṣèlú ará orílè-èdè Argentina journalist, tì wọ̀n sípò arẹ orílè-èdè Argentina láàrin ọjọ́ kinní oṣù kàrún ọdún 1958 sí ọjọ́ kokandinlogbon oṣù kẹta ọdún 1962 nígbà tí wón gbà ijọba lọ́wọ́ rẹ̀.
Ìgbésíayé
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wón bí Arturo Frondizi ní ìlú Paso de los Libres, Argentina ní ọdun 1908. Ọmọ Isabella Ércoli de Frondizi ati Giulio Frondizi ní se.
Awọn amì ẹ̀yẹ
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ẹ̀yẹ
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ami ẹyẹ | orílè-èdè | Ọjọ́ | |
---|---|---|---|
Grand Collar of the Order of the Condor of the Andes | Bolivia | 8 July 1961 | |
Collar of the Order of Merit | Chile | 1 July 1958 | |
Knight Grand Cross of the Order of the Legion of Honour | France | 8 May 1960 | |
Grand Cross Special Class of the Order of Merit of the Federal Republic of Germany | Germany | June 1960 | |
Knight Grand Cross with collar of the Order of Merit of the Italian Republic | Italy | 11 June 1960 | |
Grand Cross of the Order of the Chrysanthemum | Japan | 14 December 1961 | |
Collar of the Order of the Aztec Eagle | Mexico | 21 January 1960 | |
Grand Cross of the Order of the Netherlands Lion | Netherlands | 1 July 1960 | |
Grand Cross of the Order of the Sun of Peru | Peru | 17 April 1958 | |
Knight of the Collar of the Order of Isabella the Catholic | Spain | 7 July 1960 | |
Knight Grand Cross of the Order of Chula Chom Klao[1] | Thailand | 8 December 1961 | |
Honorary Knight Grand Cross of the Order of St Michael and St George | United Kingdom | 4 July 1960 |
Ami ẹkọ idanilola
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Peru: University of San Marcos, 1958
- Hawaii: University of Hawái, 1961
- Italy: University of Perugia, 1960
- Japan: Waseda University, 1961
- Spain: University of Madrid, 1960
- Thailand: Thammasat University, 1961
- United States: Fordham university, 1959
Àmì ẹ̀yẹ ati dídágánjíá
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Argentina: Konex of honour, 1998
- Japan: Key to the city of tokyo, 1960
- Spain: Key to the city of madrid, 1960
- Uruguay: Uruguayan Parliamentary Distinction, 1958
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ ราชกิจจานุเบกษา, ประกาศสำนักนายกรัฐมนตรี เรื่อง พระราชทานเครื่องราชอิสริยาภรณ์ Archived 2016-03-04 at the Wayback Machine., เล่ม 79, ตอน 22 ง, 6 มีนาคม พ.ศ. 2505, หน้า 558