Jump to content

Isaac Babalola Akinyele

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Oba Isaac Babalola Akinyele, OBE, KBE (April 18, 1882 – May 30, 1964) ni Olubadan akoko to gun ori ite gege bi oba. O gun ori ite ni 1955 o si wa ni be titi di ojo iku re ni 1964