Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 27 Oṣù Kẹrin
Ìrísí
Ọjọ́ 27 Oṣù Kẹrin: Ọjọ́ Ìlómìnira ní Tógò (1960) àti Sierra Leone (1961)
- 1950 – Ápártáìdì: Ní orílẹ́-édé Gúúsù Áfríkà, Ìṣe-òfin Àdúgbò Oníkákukú di òfin oníbiiṣẹ́, èyí ya àwọn ẹ̀yà sí ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀.
- 1974 – Àwọn ènìyàn 10,000 ṣèwọ́de ní Washington, D.C., wọ́n bèrè fún ìlékúrò Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà Richard Nixon.
- 1981 – Xerox PARC gbé èkúté kọ̀mpútà jáde.
- 1993 – Gbogbo àwọn ọmọ Ẹgbẹ́ agbá bọ́ọ́lù-ẹlésẹ̀ ọlórílẹ̀-èdè Zambia kú nínú ìjàmbá bàálù tó ṣẹlẹ̀ ní Libreville, Gabon nígbà tí wọ́n únlọ sí Dakar, Senegal.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1822 – Ulysses S. Grant, Ààrẹ Orílẹ̀-ẹ̀dè Amẹ́ríkà 18k (al. 1885)
- 1927 – Coretta Scott King, alákitiyan ará Amẹ́ríkà (al. 2006)
- 1945 – August Wilson, olùkòwé eré dírámà ará Amẹ́ríkà (al. 2005)
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1937 – Antonio Gramsci (fọ́tò), olùkọ̀wé àti olóṣèlú ará Itálíà (ib. 1891)
- 1969 – René Barrientos, Ààrẹ ilẹ̀ Bolivia (ib. 1919)
- 1972 – Kwame Nkrumah, olórí ilẹ̀ Ghánà (ib. 1909)