Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 3 Oṣù Kẹ̀wá
Appearance
- 1985 – Ọkọ̀-àlọbọ̀ Òfurufú Atlantis ṣe ìgbéra ìfòlókè àkọ́kọ́ rẹ̀. (Ìránlọ STS-51-J).
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1954 – Al Sharpton, alákitiyan àti òjíṣẹ́ ará Amẹ́ríkà
- 1975 – India Arie, akọrin àti olórin ará Amẹ́ríkà
- 1975 – Talib Kweli, olórin rap ará Amẹ́ríkà
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1997 – Adekunle Ajasin, olóṣèlú ará Nàìjíríà (ib. 1908)
- 1999 – Akio Morita, oníṣòwò ará Japani àti olúdásílẹ̀ ilẹ́-iṣẹ́ Sony (ib. 1921)
- 2007 – M. N. Vijayan, olúkọ̀wé ará India (ib. 1930)