Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 1 Oṣù Kẹ̀wá
Ìrísí
Ọjọ́ 1 Oṣù Kẹ̀wá: Ọjọ́ Ọmọ Orílẹ̀-èdè ní Orílẹ̀-èdè Olómìnira Ará ilẹ̀ Ṣáínà (1949); Ọjọ́ Ìlómìnira ní Kipru àti Nàìjíríà (àwọn méjéèjì 1960), Tuvalu (1978) àti Palau (1994)
- 1960 - Abubakar Tafawa Balewa di Alákóso Àgbà ìjọba Nàìjíríà lẹ́yìn ìgbòmìnira.
- 1963 - Nàìjíríà (fọ́tò àsìá) di orílẹ̀-èdè olómìnira pẹ̀lú Nnamdi Azikiwe gẹ́gẹ́ bíi Ààrẹ àkọ́kọ́.
- 1979 - Ìbẹ̀rẹ̀ Ìgba Òṣèlú Èkejì ní Nàìjíríà pẹ̀lú ìbúrá Shehu Shagari gẹ́gẹ́ bíi Ààrẹ ilẹ̀ Nàìjíríà.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1924 - Jimmy Carter - Olóṣèlú àti Ààrẹ ilẹ̀ Amẹ́ríkà
- 1959 - Youssou N'Dour, akọrin ará Senegal
- 1966 – George Weah, agbábọ́ọ̀lù-ẹlẹ́sẹ̀ àti olóṣèlú ará Làìbéríà
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1404 - Pópù Boniface 9k (ib. 1356)
- 1942 – Ants Piip, Alákóso Àgbà ilẹ̀ Estóníà (ib. 1884)