Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 6 Oṣù Kàrún
Ìrísí
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1951 – Samuel Doe, Ààrẹ ilẹ̀ Làìbéríà (al. 1990)
- 1953 – Tony Blair, alákóso àgbà ilẹ̀ Brítánì (1997–2007)
- 1953 – Lynn Whitfield, òṣeré ará Amẹ́ríkà
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1862 – Henry David Thoreau, olùkòwé ará Amẹ́ríkà (ib. 1817)
- 1992 – Marlene Dietrich, òṣeré ará Jẹ́mánì (ib. 1901)