Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 4 Oṣù Kàrún
Appearance
- 1904 – Orílẹ̀-èdè Amẹ̀ríkà bẹ̀rẹ̀ kíkọ́ Ìladò Panamá.
- 1959 – Àwọn Ẹ̀bùn Grammy wáyé fún ìgbà àkọ́kọ́.
- 1979 – Margaret Thatcher di obìnrin àkọ́kọ́ tó jẹ́ Alákóso Àgbà ilẹ̀ Brítánì.
- 2002 – Bàálù ìfòlókè EAS Airlines BAC 1-11-500 já bọ́ ní Kano, Nigeria lẹ́yìn ìgbàdíẹ̀ tó gbéra, àwọn ènìyàn tó tó 148 ni wọ́n kú.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1928 – Hosni Mubarak, Ààrẹ ilẹ̀ Egypti (al. 2020)
- 1930 – Katherine Jackson, ìyá àwọn ọmọ ẹbí Jackson olọ́rin
- 1953 – Oleta Adams, akọrin ará Amẹ́ríkà
Àwọn aláìsí lóòní...
- 2012 – Rashidi Yekini, agbábọ́ọ̀lù-ẹlẹ́sẹ̀ ará Nàìjíríà (íb. 1963)
- 2014 – Jean-Paul Ngoupandé, Central African politician, Prime Minister of the Central African Republic (b. 1948)
- 2016 – Jean-Baptiste Bagaza, Burundian politician (b. 1946)