Èdè Kóngò
Kongo | |
---|---|
Kikongo | |
Sísọ ní | Angola Democratic Republic of the Congo Republic of the Congo |
Agbègbè | Central Africa |
Ìye àwọn afisọ̀rọ̀ | 7 million |
Èdè ìbátan | |
Lílò bíi oníbiṣẹ́ | |
Àkóso lọ́wọ́ | Kòsí àkóso oníbiṣẹ́ |
Àwọn àmìọ̀rọ̀ èdè | |
ISO 639-1 | kg |
ISO 639-2 | kon |
ISO 639-3 | kon |
Kikongo tabi ede Kongo je ede Bantu ti awon eya Bakongo ati Bandundu n so.
A
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Èdè tí àwọn ènìyàn wọ̀nyí ń sọ ni Kitumba, òun ta ń pè ní Kongó ní n ǹkan ṣe pẹ̀lú àpapọ̀ àwọn èdè Bantu. Àwọn ibi tí ati n sọ èdè yìí ni: Angola, Congo, Crabon ati Zoure.
Ní àarin odún (1960) sí Ọdún (1996) àwọn tí ó n sọ èdè yìí dín díẹ̀ ni mílíọ̀nù mọ́kànlá. Àkọtọ́ èdè wọn muná dóko; ṣùgbọ́n wọn kìí lo àmì ohùn lórí gbogbo ọ̀rọ̀ wọn. Àkọtọ wọn tó wuyì yìí lo mú kí ohun èdè wọn dín kù ní lílò.
B
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Èdè Kongo
Kongo tàbí Kikongo – ó jẹ́ èdè Bantu, àwọn ènìyàn Bakongo ni wọn ń sọ ọ́. Ààrin ilẹ̀ Afíríkà ni ó wà. Àwọn tí wọ́n ń sọ ọ́ jẹ́ mílíọ̀nù méje ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn tí wọ́n kó ní ẹrú ní ilẹ̀ Afíríkà tí wọ́n sì tà wọ́n fún America ni wọ́n ń sọ èdè yìí. Àwọn bí i mílíọ̀nù ni wọ́n ń lo èdè yìí gẹ́gẹ́ bí èdè méjì.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |