Nuella Njubigbo: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò
Macdanpets (ọ̀rọ̀ | àfikún) No edit summary Àwọn àlẹ̀mọ́: Àtúnṣe ojú fóónù Àtúnṣe ojú fóónù Advanced mobile edit |
Macdanpets (ọ̀rọ̀ | àfikún) No edit summary Àwọn àlẹ̀mọ́: Àtúnṣe ojú fóónù Àtúnṣe ojú fóónù Advanced mobile edit |
||
Ìlà 20: | Ìlà 20: | ||
==Ìgbà èwe àti ẹ̀kọ́ rẹ̀== |
==Ìgbà èwe àti ẹ̀kọ́ rẹ̀== |
||
Wọ́n bí Nuella Njubigbo lọ́jọ́ kejìdínlógún oṣù kẹta ọdún 1984 ní Ìpínlẹ̀ Anambra lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ìpínlẹ̀ yìí ló ti kàwé àkọ́bẹ̀rẹ̀ àti gírámà.<ref>https://ab-tc.com/nuella-njubigbo-biography-career-awards-and-net-worth/</ref>. Ó kàwé gbàwé ẹ̀rí nínú ìmọ̀ ètò ìṣèjọba àti àkóso àwùjọ, (Government and Public Administration) ní [[Imo State University]]. Ó sìn orílẹ̀ èdè bàbá rẹ̀ ní [[Ìpínlẹ̀ Delta]] fún àkànṣe ìsìnlú, [[National Youth Service Corps]].<ref>{{cite web | url=http://www.bellanaija.com/2013/10/11/nollywood-actress-nuella-njubigbo-completes-her-nysc-programme | title=Nollywood Actress completes NYSC Program | publisher=bellanaija.com | accessdate=19 April 2014}}</ref> |

Lọ́jọ́ kokàndínlọ́gbọ̀n oṣù kẹta ọdún 2014, òun àti gbajúmọ̀ olùdarí sinimá àgbéléwò, [[Tchidi Chikere]] fẹ́ ara wọn. Awuyewuye pọ̀ lórí ìgbéyàwó wọn nítorí pé ọkọ rẹ̀ ti kọ́kọ́ fẹ́ ìyàwó kan tẹ́lẹ̀ kí wọ́n tó fẹ́ ara wọn. Sophia Chikere, tí òun náà jẹ́ òṣèrébìnrin ni ọkọ rẹ̀ kọ́kọ́ fẹ́, tí wọ́n sìn ti bímọ fún ara wọn. .<ref>{{cite web | url=http://www.informationng.com/2014/03/tchidi-chikeres-buddy-blasts-him-for-abandoning-wife-for-nuella-njubigbo.html | title=Tchidi Chikere blasted for abandoning wife | publisher=informationng.com | accessdate=19 April 2014}}</ref><ref>{{cite web | url=http://dailypost.ng/2014/03/30/nuella-njubigbo-weds-tchidi-chikere-photos/ | title=Nuella weds Tchidi amidst several controversy | publisher=dailypost.ng | accessdate=19 April 2014}}</ref> Tchidi, ọkọ rẹ̀ kò ṣàìṣàlàyé ìdí tí ìgbéyàwó àkọ́kọ́ fi forí ṣánpán lẹ́yìn ọ̀pọ̀lọpọ̀ awuyewuye wọ̀nyí.<ref>{{cite web | url=http://www.africanspotlight.com/2014/03/29/photos-actress-nuella-njubigbo-finally-weds-tchidi-chikere/ | title=Actress finally weds Tchidi | publisher=africanspotlight.com | accessdate=19 April 2014}}</ref><ref>{{cite web | url=http://www.vanguardngr.com/2014/03/nuella-njubigbo-speaks-marriage-tchidi-chikere/ | title=Nuella speaks on marriage to Tchidi | publisher=vanguardngr.com | accessdate=19 April 2014}}</ref> Wọ́n bímọ kan fún ara wọn lẹ́yìn [[ìgbéyàwó]] náà. |
|||
Ó dara pọ̀ mọ́ iṣẹ́ tíátà lọ́dún 1999, eré àkọ́kọ́ tó ṣe ni “Royal Destiny”. Lẹ́yìn náà, ó ti kópa nínú sinimá tí ó ti ju àádọ́rùnún lọ. Ó ti bá àwọn gbajúmọ̀ oṣèré bí i [[Ini Edo]], [[Mercy Johnson]], [[Desmond Elliot]], [[Uche Jombo]], [[Genevieve Nnaji], [[John Okafor]], [[Pete Edochie]] ati [[Ken Eric's]] ṣeré pọ̀. <ref>https://austinemedia.com/nuella-njubigbo-biography-net-worth/ </ref><ref> |
|||
https://ab-tc.com/nuella-njubigbo-biography-career-awards-and-net-worth/ |
|||
</ref>. |
|||
==Àwọn ìtọ́kasí== |
==Àwọn ìtọ́kasí== |
Àtúnyẹ̀wò ní 20:37, 3 Oṣù Bélú 2020
Nuella Njubigbo | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Ìpínlẹ̀ Anambra |
Orílẹ̀-èdè | Nàìjíríà |
Iṣẹ́ | Òṣèrébìnrin Screen writer |
Nuella Njubigbo jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin, oǹkọ̀tàn sinimá àgbéléwò, arẹwà àti olóòtú tẹlifíṣàn ọmọ Nàìjíríà.[1] Ó dara pọ̀ mọ́ iṣẹ́ eré tíátà lọ́dún 1999.[2] wọ́n sìn yàn án fún ìdíje àmìn ẹ̀yẹ 2012 Nollywood Movies Awardsfún oṣèré tó ń dàgbà jù lọ lọ́dún 2012 .[3][4][5][6][7]
Ìgbà èwe àti ẹ̀kọ́ rẹ̀
Wọ́n bí Nuella Njubigbo lọ́jọ́ kejìdínlógún oṣù kẹta ọdún 1984 ní Ìpínlẹ̀ Anambra lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ìpínlẹ̀ yìí ló ti kàwé àkọ́bẹ̀rẹ̀ àti gírámà.[8]. Ó kàwé gbàwé ẹ̀rí nínú ìmọ̀ ètò ìṣèjọba àti àkóso àwùjọ, (Government and Public Administration) ní Imo State University. Ó sìn orílẹ̀ èdè bàbá rẹ̀ ní Ìpínlẹ̀ Delta fún àkànṣe ìsìnlú, National Youth Service Corps.[9]
Lọ́jọ́ kokàndínlọ́gbọ̀n oṣù kẹta ọdún 2014, òun àti gbajúmọ̀ olùdarí sinimá àgbéléwò, Tchidi Chikere fẹ́ ara wọn. Awuyewuye pọ̀ lórí ìgbéyàwó wọn nítorí pé ọkọ rẹ̀ ti kọ́kọ́ fẹ́ ìyàwó kan tẹ́lẹ̀ kí wọ́n tó fẹ́ ara wọn. Sophia Chikere, tí òun náà jẹ́ òṣèrébìnrin ni ọkọ rẹ̀ kọ́kọ́ fẹ́, tí wọ́n sìn ti bímọ fún ara wọn. .[10][11] Tchidi, ọkọ rẹ̀ kò ṣàìṣàlàyé ìdí tí ìgbéyàwó àkọ́kọ́ fi forí ṣánpán lẹ́yìn ọ̀pọ̀lọpọ̀ awuyewuye wọ̀nyí.[12][13] Wọ́n bímọ kan fún ara wọn lẹ́yìn ìgbéyàwó náà. Ó dara pọ̀ mọ́ iṣẹ́ tíátà lọ́dún 1999, eré àkọ́kọ́ tó ṣe ni “Royal Destiny”. Lẹ́yìn náà, ó ti kópa nínú sinimá tí ó ti ju àádọ́rùnún lọ. Ó ti bá àwọn gbajúmọ̀ oṣèré bí i Ini Edo, Mercy Johnson, Desmond Elliot, Uche Jombo, [[Genevieve Nnaji], John Okafor, Pete Edochie ati Ken Eric's ṣeré pọ̀. [14][15].
Àwọn ìtọ́kasí
- ↑ https://ab-tc.com/nuella-njubigbo-biography-career-awards-and-net-worth/
- ↑ https://ab-tc.com/nuella-njubigbo-biography-career-awards-and-net-worth/
- ↑ "Nuella Njubigbo Biography on AfricanSeer". africanseer.com. Retrieved 18 April 2014.
- ↑ "Nuella Njubigbo". Archived from the original on 20 April 2014. Retrieved 19 April 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Hot Pants actress acquires new SUV". modernghana.com. Retrieved 18 April 2014.
- ↑ "Nuella on iMDb". imdb.com. Retrieved 19 April 2014.
- ↑ "Nella releases hot new photos". informationng.com. Retrieved 19 April 2014.
- ↑ https://ab-tc.com/nuella-njubigbo-biography-career-awards-and-net-worth/
- ↑ "Nollywood Actress completes NYSC Program". bellanaija.com. Retrieved 19 April 2014.
- ↑ "Tchidi Chikere blasted for abandoning wife". informationng.com. Retrieved 19 April 2014.
- ↑ "Nuella weds Tchidi amidst several controversy". dailypost.ng. Retrieved 19 April 2014.
- ↑ "Actress finally weds Tchidi". africanspotlight.com. Retrieved 19 April 2014.
- ↑ "Nuella speaks on marriage to Tchidi". vanguardngr.com. Retrieved 19 April 2014.
- ↑ https://austinemedia.com/nuella-njubigbo-biography-net-worth/
- ↑ https://ab-tc.com/nuella-njubigbo-biography-career-awards-and-net-worth/