Ààrẹ ilẹ̀ Afghanístàn
Ìrísí
Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Olómìnira Onímàle ilẹ̀ Afghanístàn President of the Islamic Republic of Afghanistan د افغانستان د اسلامي جمهوریت رئیس نوماند نامزد رئيس جمهوری اسلامی افغانستان | |
---|---|
Style | The Honourable (Formal) His Excellency (Diplomatic) |
Residence | Presidential Citadel, Kabul, Afghanistan |
Appointer | Direct election |
Iye ìgbà | Ọdún márùún, renewable once |
Ẹni àkọ́kọ́ | Mohammed Daoud Khan (Republic) Hamid Karzai (Islamic Republic) |
Formation | 17 July 1973 (Republic) 7 December 2004 (Islamic Republic) |
Deputy | Vice President of Afghanistan |
Owó osù | 960,000 AFN per month[1] |
Website | Office of the President |
Àyọkà yìí jẹ́ ìkan nínú àwọn àyọkà nípa ìṣèlú àti ìjọba ilẹ̀ Afghanístàn |
---|
Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Olómìnira Onímàle ilẹ̀ Afghanístàn ni olórí orílẹ̀-èdè àti olórí ìjọba ilẹ̀ Afghanístàn. Ààrẹ lọ́wọ́lọ́wọ́ ni Ashraf Ghani.
Kí wọn ó tó ṣe ìdásílẹ̀ ipò ààrẹ Orílẹ̀-èdè Olómìnira Onímàle ilẹ̀ Afghanístàn ní 2004, Afghanístàn tilẹ̀ ti jẹ́ Orílẹ̀-èdè olómìnira onímàle láti àrin ọdún 1973 àti 1992 àti láti ọdún 2001 ṣíwájú. Kí ó tó di ọdún 1973, ibẹ̀ jẹ́ mímọ̀ bíi ilẹ̀ọba. Ní àrin ọdún 1992 àti 2001, nígbà ogun abẹ́lé, Afghanístàn jẹ́ mímọ́ bíi Orílẹ̀-èdè Onímàle ilẹ̀ Afghanístàn, àti lẹ́yìn náà bíi Ẹ́míráti Onímàle ilẹ̀ Afghanístàn.
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Wadsam (1 June 2013). "Afghanistan’s lower house approves President Karzai’s salary and expenses amount".