Olórí orílẹ̀-èdè
Ìrísí
Àwọn olórí orílẹ̀-èdè àwọn orísirísi orílẹ̀-èdè:
- Emmanuel Macron, Ààrẹ ilẹ̀ Fránsì
- Ram Nath Kovind, Ààrẹ ilẹ̀ Índíà
- Joe Biden, Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà
Àdàkọ:Politics sidebar Olórí orílẹ̀-èdè ni ẹni aráàlú kan tí óún dúró fún orílẹ̀ ìjọba kan lábẹ́ àṣẹ[1] ní ìṣọ̀kan àti lábẹ́ òfin rẹ̀. Bí irú ìjọba àti ìpín àwọn agbára ìjọba orílẹ̀-èdè kọ̀ọ̀kan bá ṣe rí, olórí orílẹ̀-èdè le jẹ́ fún oyè lásán tàbí lẹ́ẹ̀kannáà bíi olórí ìjọba àti ìṣẹ́ míràn.