Àkójọpọ̀ ayẹyẹ ọdún ìbílẹ̀ Ghana
Ìrísí
Àwọn ayẹyẹ ọdún ìbílẹ̀ ní orílẹ̀ èdè Ghana wọ́n máa ń ṣe àwọn ọdún yìí fún onírúurú àwọn ìdí kan sí èkejì bí ó bá ṣe kan ẹ̀yà kan sí tàbí irúfẹ́ àṣà bẹ́ẹ̀. Àwọn ọdún kọ̀ọ̀kan ló ní àwọn ìtàn tí ó rọ mọ́ wọn èyí tí ó máa ń rọ̀ mọ́ àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ kan. Àpẹẹrẹ àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ bẹ́ẹ̀ ni; ebi, Ìṣípòpadà, láti fọ ìlú mọ́, abbl...
Ìdí tí wọ́n fi máa ń ṣe ayẹyẹ
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àwọn ìwúlò pàtàkì tí ó wà fún ṣíṣe ayẹyẹ kan:
- Gbígbèèrò àwọn iṣẹ́ àkànṣe fún ìdàgbàsókè ìlú: Wọ́n máa ń lo àwọn ayẹyẹ ọdún ìbílẹ̀ láti pàdé papọ̀ pẹ̀lú àwọn ará ìlú láti le jíròrò lórí àwọn iṣẹ́ àkànṣe tí ó le mú ìdàgbàsókè bá àwùjọ.
- Fífọ àwọn òrìṣà mọ́: Wọ́n máa ń lo àkókò àti ìgbà yìí láti tún ojúbọ àwọn òrìṣà ṣe kí wọ́n ó sì ṣe àwọn ètùtù tí ó ṣe kókó.
- Ìdúpẹ́: Wọ́n máa ń lo àwọn ayẹyẹ ọdún láti fi dúpẹ́ lọ́wọ́ Elédùmarè àti àwọn òrìṣà fún ìtọ́sọ́nà àti ìdáàbòbò wọn.
- Ipa òṣèlú àti ti ìjọba àpapọ̀: Àwọn ènìyàn tí wọ́n jẹ́ èèkàn nínú ìlú àti àwọn tí wọ́n ń bẹ ní ìṣàkóso ìlú ni wọ́n máa ń fi ìwé pè láti wá ṣàlàyé nípa ètò tí ìjọba ni fún àwọn ará ìlú.
- Láti paná ìjà:Wọ́n máa ń lo àwọn ọdún ìbílẹ̀ láti parí ìjà láàrin àwọn ẹbí, ará, ọ̀rẹ́ àti ojúlùmọ̀ kí àlàáfíà lè jọba.
- Láti gbé àṣà àti ìrìnnà afẹ́ lárugẹ: Àwọn ayẹyẹ ìbílẹ̀ kan wà ní orílẹ̀ èdè Ghana tí ó máa ń fa ojú àwọn ènìyàn láti orílẹ̀ èdè mìíràn wá. Lára àwọn ayẹyẹ bẹ́ẹ̀ ni a ti rí - Ayẹyẹ ọdún Aboakyir. Ìrìnàjò afẹ́ losi orílẹ̀ èdè Ghana jẹ́ ọ̀nà kẹta tí owó ń gbà wọlé láti ilẹ̀ òkèèrè
Àkójọpọ̀ àwọn ayẹyẹ ọdún ìbílẹ̀ àti oṣù tí wọ́n máa ń ṣe wọ́n
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ayẹyẹ ọdún ìbílẹ̀ ní orílẹ̀-èdè Ghana | Àwọn ẹ̀yà tí wọ́n máa ń ṣe é |
---|---|
Bakatue[1] | Elmina (Fante) |
Homowo[2] | Ga |
Aboakyer[3] | Efutu (Winneba) |
Kundum[4] | Nzema[5] |
Fao | NavrongoÀdàkọ:Cn |
Kpini Chugu (Guinea fowl Festival) | Dagombas, Mamprusis, Nanumbas, Kokombas and Basaris[6] |
Ohum[7] | Akim,[8] Akuapem[9] |
Hogbetsotso[10] | Anlo[11] |
Ngmayem | Krobo[12] |
Volo (Me/Lomo) | Volos |
Yam[13] | Ho[14] |
Buɣum Chuɣu (Fire Festival)[15][16]al) | Dagomba[17] Dagbon, Gonja, Mamprusi and Nanumba |
Beng | Gonja[18] |
Lukusi | Ve (Near Hohoe) |
Danyiba | Kpando[19] |
Fetu Afahye[20] | Oguaa[21] (Cape Coast) |
Adae Kese | Ashanti[22] Etc. |
Adae[23] | Asante,[21]Akim,[8] Akwamu[24] |
Asafotufiam[25] | Ada[26] |
Dzawuwu Festival[27] | Agave[28] |
Fiok[29] | Builsa |
Apafram[30] | Akwamu[31] |
Osudoku Festival[32] | Asutsuare[33] |
Afenorto Festival[30] | Mepe[34] |
Papa Festival[35] | Kumawu[36] |
Opemso FestivalÀdàkọ:Cn | Kokofu-Anyinam |
Ɔvazu FestivalÀdàkọ:Cn | Akposo |
Damba festival | Dagomba people, Gonja, Mamprusi |
Àkójọpọ̀ tí ó wà ní ìsàlẹ̀ yìí ni àwọn ayẹyẹ ọdún ìbílẹ̀, àwọn ọdún ẹ̀sìn tí wọ́n wà fún ìrántí tí wọ́n máa ń ṣe lọ́dọọdún ní orílẹ̀-èdè Ghana. [37] Àkójọpọ̀ yìí le má kún fún gbogbo àwọn ọdún tí wọ́n ń ṣe lórílẹ̀-èdè Ghana.
Fún ìṣèrántí ọdún ọ̀gbìn
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Fún ìṣèrántí Ìṣípòpadà
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Fún ẹ̀sìn
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àwọn tó kù
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Agadevmi (Have, Afadzato South District, Volta Region)
- ọdún Agbamevo
- Ahobaa
- ọdún Akwambo
- ọdún Akwantutenten (Worawora, Volta Region)
- ọdún Amu
- Apoor
- Asafotu-fiam (Ada ní ẹkùn ìlà-oòrùn)
- ọdún Asafotufiam
- ọdún Asafua
- ọdún iṣu Asogli
- Atu-Ho-Akye (Ejisu, Ashanti Region)
- ọdún Ayimagonu
- ọdún Ayimagonu
- ọdún Bakatue
- ọdún Beng
- Chale Wote Street Art Festival
- ọdún Damba
- ọdún Danso Abaim àti Ntoa Fukokuese (Techimentia & Nkoranza, ní ẹkùn Brong Ahafo)
- ọdún Dipo (Manya Krobo, Yilo Krobo, ní ẹkùn ìlà-oòrùn)
- ọdún Dzawuwu
- Dzohayem (Osudoku, Greater Accra)
- ọdún Edina Buronya
- Eiok (ọdún ogun)
- Fetu Afahye
- Fiok ( Sandema by the Builsas)
- Gbidukor
- Gbidukor
- Glimetoto
- Golob (Tengzung, Upper East Region)
- Gologo
- Gwolgu
- Jintigi (All Gonja Towns, Northern Region)
- Kente (Bonwire, Ashanti Region)
- Kloyosikplem festival (Ghana Eastern region)[39]
- Kobine
- Kpalikpakpa zã (Kpalime Traditional Area in the Volta Region)
- Kpini-Kyiu Festival (Wa & Tongu, in the Upper East Region)
- Kpledjoo
- Kundum
- Kwafie
- Meet Me There Weekender
- Mmoanniko
- Nkyidwo (Essumeja)
- Ntoa Fokuose
- Nyidwoo
- Odambea
- Odwira
- Paragbeile
- ọdún ìresì (Akpafu, ní Volta)
- Sasadu
- Sometutuza (Keta)
- Tenghana (Wa & Tongu, in the Upper East Region)]]
- Tongu Upper East Region
- Wilaa (Takpo, Upper West Region)
- Yaa Asantewaa
Oti Region)]]
- Ɔvazu (Akposokubi) Oti Region, formally Volta/Trans-Volta Togoland
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Bakatue Festival , 2019 - GWS Online GH". www.ghanawebsolutions.com. Retrieved 2019-01-26.
- ↑ "Homowo Festival". www.ghanaweb.com. Retrieved 2019-01-26.
- ↑ "Aboakyer Festival". www.ghanaweb.com. Retrieved 2019-01-26.
- ↑ "Kundum Festival". www.travel-to-discover-ghana.com. Retrieved 2019-01-26.
- ↑ "National Commission On Culture". www.ghanaculture.gov.gh. Retrieved 2019-01-27.
- ↑ "The Northern Region of Ghana - ghanagrio.com - ghanagrio.com". www.ghanagrio.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-10-02.
- ↑ "OHUM STARTS". Modern Ghana. 2012-08-28. Retrieved 2019-01-27.
- ↑ 8.0 8.1 "Akyem People of Ghana.". Africani Sankofa. 2017-11-22. Retrieved 2019-01-27.
- ↑ "Choirmaster for Awukugua Ohum". Graphic Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-06-23.
- ↑ "Hogbetsotso Festival". www.travel-to-discover-ghana.com. Retrieved 2019-01-26.
- ↑ "The Anlo-Ewe people of Ghana". This Is Africa Lifestyle. 2017-07-10. Retrieved 2019-01-27.
- ↑ "The Krobo People of Ghana to 1892: A Political and Social History". Ohio University Press • Swallow Press. Retrieved 2019-01-27.
- ↑ "Asogli promises another exciting yam festival this year". www.myjoyonline.com. 2017-09-06. Retrieved 2019-01-26.
- ↑ "Ghana Districts: A repository of all Local Assemblies in Ghana". www.ghanadistricts.com. Retrieved 2019-01-27.
- ↑ "Ghana Festivals". ghanakey.com. Retrieved 2020-01-21.
- ↑ Cof, Katja (2016-03-05). "Buɣum Chuɣu Fire Festival in Northern Ghana". Safari Junkie. Retrieved 2019-01-26.
- ↑ "Dagomba kingdom | historical kingdom, Africa". Encyclopedia Britannica. Retrieved 2019-01-27.
- ↑ "A Brief History of Northern Ghana - Focus on Gonja". www.ghanaweb.com. 30 November 2001. Retrieved 2019-01-27.
- ↑ "Kpando Municipal Assembly – Official Website of Kpando Municipal Assembly". Retrieved 2019-01-27.
- ↑ "Oguaa Fetu Afahye Festival, Cape Coast". Afro Tourism. 2017-03-10. Retrieved 2019-01-26.
- ↑ 21.0 21.1 "Oguaa Fetu Afahye Festival, Cape Coast". Afro Tourism. 2017-03-10. Retrieved 2019-01-27.
- ↑ "Asante | people". Encyclopedia Britannica. Retrieved 2019-01-27.
- ↑ "Adae | Akan festival". Encyclopedia Britannica. Retrieved 2019-01-27.
- ↑ "Ghana Ethnic Groups, Akwamu". www.ghanaweb.com. Retrieved 2019-01-27.
- ↑ "About". Ada Asafotufiami Festival. 2010-12-13. Retrieved 2019-01-26.
- ↑ "ADA PEOPLE: THE TRADITIONALIST DANGME PEOPLE AND THEIR UNIQUE ASAFOTUFIAMI FESTIVAL". ADA PEOPLE. Retrieved 2019-01-27.
- ↑ Editor (2016-02-24). "Festivals in Ghana". touringghana.com. Retrieved 2019-01-26.
- ↑ "Agave Afedome - GhanaPlaceNames". sites.google.com. Retrieved 2019-01-27.
- ↑ "FESTIVALS OF GHANA". www2.gsu.edu. Retrieved 2019-01-26.
- ↑ 30.0 30.1 Dzaho, Jerome. "Festivals". Ghana Tourism Authority. Retrieved 2019-01-26.
- ↑ "Akwamu | historical state, Africa". Encyclopedia Britannica. Retrieved 2019-01-27.
- ↑ "Osudoku Aadegbor Festival Launched". Modern Ghana. 2018-08-07. Retrieved 2019-01-26.
- ↑ "Figure 1: Shai Osudoku District Map (where Asutuare Area Council lies)....". ResearchGate. Retrieved 2019-01-27.
- ↑ "Mepe Community Site". mepe.objectis.net. Retrieved 2019-01-27.
- ↑ "Papa Festival". TheFreeDictionary.com. Retrieved 2019-01-26.
- ↑ "National Commission On Culture". www.ghanaculture.gov.gh. Retrieved 2019-01-27.
- ↑ "Festivals". GhanaWeb. Retrieved 23 October 2014.
- ↑ "Festivals in Ghana". Dear Ghana. Retrieved 23 October 2014.
- ↑ "Festivals in Ghana". www.ghanaweb.com. Retrieved 27 December 2011.