Àtòjọ àwọn Ilé-Ìwòsàn ti ìjọba àpapọ̀ Ilẹ̀ Nàìjíríà
Ìrísí
Àtòjọ àwọn Ilé-Ìwòsàn ìjọba àpapọ̀ ti Ilẹ̀ Nàìjíríà ni :
- University of Nigeria Teaching Hospital
- University of Benin Teaching Hospital ti ìlú Benin.
- University College Hospital ti ìlú Ìbàdàn[1]
- Ahmadiyya Hospital Newbussa
- Federal Health Medical Center (FHMC) ti ìlú Ọ̀wọ̀.
- National Hospital ti ìlú Àbújá
- Abia State University Teaching Hospital, ti ìlú Aba
- Imo State University Teaching Hospital, ti ìlú Orlu
- Sir Yahaya Memorial Hospital Kebbi
- ECWA Hospital ti ìlú Ẹ̀gbẹ̀ ní ìpínlẹ̀ Kogí.
- Federal Medical Center ti ìlú Abẹ́òkúta Ìpínlẹ̀ Ògùn
- ECWA Evangel Hospital, ti ìlú Jos Ìpínlẹ̀ Plateau
- Lagos University Teaching Hospital ti Ìpínlẹ̀ Èkó.[2]
- Lagos State University Teaching Hospital Ìpínlẹ̀ Èkó.
- Federal Teaching Hospital, ti ìlú Ìdó-Èkìtì ní ìpínlẹ̀ Ekiti.
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "UCH IBADAN – UNIVERSITY COLLEGE HOSPITAL". UCH IBADAN – UNIVERSITY COLLEGE HOSPITAL. Retrieved 2020-01-12.
- ↑ Scott-Emuakpor, Ajovi (2010-04-01). "The evolution of health care systems in Nigeria: Which way forward in the twenty-first century". Nigerian Medical Journal 51 (2). http://www.nigeriamedj.com/article.asp?issn=0300-1652;year=2010;volume=51;issue=2;spage=53;epage=65;aulast=Scott-Emuakpor. Retrieved 2020-01-12.
- ↑ Okpalauwaekwe, Udoka; Mela, Mansfield; Oji, Chioma (2017-03-06). "Knowledge of and Attitude to Mental Illnesses in Nigeria: A Scoping Review". Integrative Journal of Global Health 1 (1). ISSN 2576-3911. http://www.imedpub.com/articles/knowledge-of-and-attitude-to-mental-illnesses-in-nigeria-a-scoping-review.php?aid=18642. Retrieved 2020-01-12.