Jump to content

Àwọn ọmọ Nàìjíríà Amẹ́ríkà

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Àwọn ọmọ Nàìjíríà Amẹ́ríkà
Àwọn ọmọ Nàìjíríà Amẹ́ríkà
Nigerian Americans
Àpapọ̀ iye oníbùgbé
380,785 total, 2016
277,027 ni wọ́n bí ní Nàìjíríà, 2012-2016
Regions with significant populations
Texas, Maryland, California, New York, Florida, Georgia, Illinois, New Jersey, Minnesota
Èdè

American English, Nigerian English, Igbo, Yoruba, Hausa, Edo, Ibibio-Anaang-Efik, Esan, Urhobo, Isoko, Idoma, Ijaw, Fulani, Kalabari, Igala, Ikwerre, Tiv, Ebira, Nembe, Etsako, Itsekiri, Nupe, Nigerian Pidgin
Others
Nigerian languages and various languages of Nigeria[1]

Ẹ̀sìn

Christianity (Protestantism, Roman Catholicism, Anglicanism)
Sunni Islam, Animism, West African Vodun, agnosticism, atheism minorities[2]

Ẹ̀yà abínibí bíbátan

Nigerian Canadians

Àwọn ọmọ Nàìjíríà Amẹ́ríkà (Nigerian Americans) ní àwọn ará Amẹ́ríkà tí wọ́n ní ìbátan mọ́ ará Nàìjíríà. Ìdíye tí American Community Survey ṣe ní ọdún 2016 sọ pé àwọn ará ìlẹ̀ Amẹ́ríkà tí wọ́n pe ara wọn ní ọmọ Nàìjíríà tó 380,785.[3] Nínú wọn, àwọn 277,027 ni wọ́n bí ní Nàìjíríà.[4]

Nigeria is both the most populous country in Africa—190.8 million as of 2018[5]—and the African country of origin with the most migrants in the United States, as of 2013.[6]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. https://books.google.com/books?id=uUFEJMGuVw4C&pg=PA16&dq=nigerian+americans+religion&hl=en&sa=X&ved=0ahUKEwix5fKV8ejoAhVOknIEHaChA3oQ6AEIJTAA#v=onepage&q=nigerian%20americans%20religion&f=false
  2. https://books.google.com/books?id=uUFEJMGuVw4C&pg=PA16&dq=nigerian+americans+religion&hl=en&sa=X&ved=0ahUKEwix5fKV8ejoAhVOknIEHaChA3oQ6AEIJTAA#v=onepage&q=nigerian%20americans%20religion&f=false
  3. "Table". Archived from the original on February 14, 2020. Retrieved 2019-10-24.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  4. "Data". Archived from the original on 2020-02-13. Retrieved 2019-10-24.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  5. "Archived copy". Archived from the original on October 29, 2017. Retrieved December 25, 2017.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  6. "Archived copy". Archived from the original on December 23, 2017. Retrieved December 25, 2017.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)