Èdè Ìdomà
Ìrísí
(Àtúnjúwe láti Idoma language)
Ìdomà | |
---|---|
Sísọ ní | Ìpínlẹ̀ Bẹ́núé, Àrin Nigeria |
Ọjọ́ ìdásílẹ̀ | 1991 |
Ẹ̀yà | Ìdomà |
Ìye àwọn afisọ̀rọ̀ | 600,000 |
Èdè ìbátan | Niger-Kóngò
|
Àwọn àmìọ̀rọ̀ èdè | |
ISO 639-3 | idu |
Ìdomà jẹ́ ẹ̀yà kan lára àwọn ẹ̀yà ilẹ̀ Nàìjíríà tí wọ́n ń sọ èdè Ìdomà ní Bẹ́núé ìpínlẹ̀ yi ni ó wà ní à́árín gbùngbùn orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Àwọn tí wọ́n ń sọ èdè yìí jẹ́ ẹgbẹ̀rún lọ́nà àádọ́rin ènìyàn. Àwọn aládùgbóò tàbí tí wọ́n jọ sún mọ́ ara wọn ni: Ibibo, Igbo, Mama àti Mumuye. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn Idoma ni wọ́n yan iṣẹ́ àgbẹ̀ láàyò.[1] [2] Wọ́n si máa ń ṣe àpọ́nlé àwọn bàbá ńlá wọn tí wọ́n ti kú.
Àwọn Ìtọ́ka sí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "About Idoma People". Idoma Land. 2008.
- ↑ Godwin, Ameh Comrade. "David Mark using University to fool Idoma people – Benue APC". D.