Èdè Ìdomà

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
Ìdomà
Sísọ ní Ìpínlẹ̀ Bẹ́núé, Àrin Nigeria
Ọjọ́ ìdásílẹ̀ 1991
Ẹ̀yà Ìdomà
Ìye àwọn afisọ̀rọ̀ 600,000
Èdè ìbátan
Àwọn àmìọ̀rọ̀ èdè
ISO 639-3 idu
Idoma.jpeg

Èdè Ìdomà tàbí Idoma jẹ́ èdè ní Àrin Nàìjíríà (ní Ìpínlẹ̀ Bẹ́núé). Èdè Idoma A lè rí Ìdomà ní ààrin gùngùn orílẹ̀ èdè Náígíríà. Àwọn tí wọ́n ń sọ èdè yìí jẹ́ igba méjì ati àádọ́ta ẹgbẹ̀rún. Àwọn aládùgbóò rẹ̀ ni Ibibo, Igbo, Mama àti Mumuye. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn Idoma ni wọ́n jẹ agbẹ. Wọ́n si máa ń se àpọ́nlé àwọn baba ńlá wọn tí wọ́n ti kú.

Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]