Àwọn ọmọ Yorùbá

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Yorùbá
Kwarastatedrummers.jpg
Kwara State drummers.
Àpapọ̀ iye oníbùgbé
Over 42 million (est.)[1]
Regions with significant populations
Nàìjíríà Nàìjíríà 41,055,000 [2]
 Benin 1,009,207+ [3]
 Ghana 350,000 [4]
 Togo 85,000 [5]
USA USA
 United Kingdom
Èdè

Yoruba, Yoruboid languages

Ẹ̀sìn

Christianity 40%, Islam 50%, Orisha veneration and Ifá 10%.

Ẹ̀yà abínibí bíbátan

Bini, Nupe, Igala, Itsekiri, Ebira

Àwọn ọmọ Yorùbá ti a pè ni ẹ̀nìyàn Yorùbá ni ibí yìí pọ̀ gan-an ni. Ilẹ̀ Yorùbá ni púpò nínú wọ́n wa ni ìpínlẹ̀ Ẹdó, Ìpínlẹ̀ Èkìtì, Èkó, Ìpínlẹ̀ Kwara, ìpínlẹ̀ Kogí, ìpínlẹ̀ Ògùn, Ìpínlẹ̀ Oǹdó, ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun, Ọ̀yọ́; àti wípé ọmọ Yorùbá wa ní orílẹ̀-èdè Olómìnira Benin (Dahomey), Sàró (Sierra Leone) àti Togo, Brazil, Cuba, Haiti, Amẹ́ríkà ati Venezuela. Àwọn Yorùbá ni wọ́n se ipò keta ni pípò ni ilè Nàìjíríà.

Àwọn Yorùbá jẹ́ àwọn ènìyàn kan ti èdè wón pín sí orísirísi. Àwọn Ìpín yíì ní a n ri; a máà lo ìpín èdè láti fi pé à èdè wa tí n se bi ti "Améríkà"; "Èkìtì"; "èkó"; "Ìjèbú"; "Ìjẹ̀ṣhà"; "Ìkálẹ̀"; "Ọ̀yó"; àti bebe lo. Láàrin èyí, la síì tún ní èdè ìfò tí nse àpẹẹrẹ èdè tó nípin si àwọn ìpín èdè tí o pọ̀. Yorùbá je ènìyàn kan ti o fẹ́ràn láti máà se áajò. Yorùbá a máà nífe ọmọ ẹnìkejì re.Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àdàkọ:Ẹ̀yà Nàìjíríà