Ìgbìrà

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
Ebira
Àpapọ̀ iye oníbùgbé
1.4 million
Regions with significant populations
Nigeria 1.4 million
Èdè

Ebira language

Ẹ̀sìn

Christianity and Islam

Igbìrà tàbí Ebira je eya eniyan ni Naijiria.

Èdè yìí jé òkan lára àwon èdè Náíjíríà. Àwon tí wón ń so ó jé mílíònù kan. Won wà ni àgbègbè Ebira ní ìpínlè Kwara, Edo, Okene àti béè béè lo. Àwon èka èdè tí ó wà ní abé rè ni Okene (Hima, Ihima) igbara (Etunno) Ebira ní ìsupò èka èdè, wón ń lò ó ní ilé ìwé.