Adebayo Alao-Akala

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Christopher Adebayo Alao-Akala
Alao-akala.jpg
Gomina Ipinle Oyo
In office
29 May, 2007 – 29 May, 2011
AsíwájúRasheed Ladoja
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí1950
Ipinle Oyo, Nigeria
Ẹgbẹ́ olóṣèlúPDP

Christopher Adébáyọ̀ Àlàó Akálà ni wọ́n bí ní ọjọ́ kẹ́ta oṣù kẹfà ọdún 1950 (3-61950) jẹ́ òṣèlú àti Gómìnà nígbà kan rí ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[1] Ní ọdún 2019, ó díje dupò Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ lẹ́ẹ̀kan si lábẹ́ ẹgbẹ́-òṣèlú ADP ṣùgbọ́n ó yára dara pọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ APC kí ìdìbò ó tó wáyé. [2]Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Christopher Alao-Akala". Wikipedia. 2006-01-12. Retrieved 2019-09-25. 
  2. "Alao-Akala dumps opposition coalition, aligns with APC". Punch Newspapers. 2015-12-15. Retrieved 2019-09-25.